Top Songs By Ebenezer Obey
Similar Songs
Lyrics
Ine ri nkan he
To fe ku pelu e ooo
Owo eni to ti sonu nko
Aye laba aye lao fi silesi duro na weyin re wo oo
Agbajowo mani
Won lo n gberudori awon omo wa emamaje kan taraka
Oni lari oooo ko ma se ni tomola ni se laye yin eda kan to leyin ni
Kaparapo ka rori
Koju telegan lagbara bami
Eshami ase
Writer(s): Ebenezer Remilekun Obey-fabiyi
Lyrics powered by www.musixmatch.com