Lyrics

FILLED UNDER: O FUN MI LEDIDI Camc Salvation14: 411 comment O fun mi l'edidi, 'Gbese nla ti mo je, B'o ti fun mi, o si rerin, Pe, "Mase gbagbe mi!" O fun mi l'edidi, O san igbese na; B'o ti fun mi, o si rerin, Wi pé, "Ma ranti mi!" N ó p'edidi na mo, B'igbese tile tan; O n so ife eni t'o san, Igbese naa fun mi. Mo wo, mo si rerin Mo tun wo, mo sokun; Eri ife Re si mi ni, N ó toju re titi. Ki tun s'edidi mo, Sugbon iranti ni! Pe gbogbo igbese mi ni, Emmanueli san. Amin
Writer(s): Public Domain Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out