album cover
Patek
album cover
00:00
00:20
00:40
01:00
01:45
02:00
02:35
00:00
02:43
Past 7 Days
Patek was discovered most frequently at around 40 seconds into the song during the past week

Music Video

Music Video

Lyrics

[Verse 1]
Even when nobody clap I dey hype up myself
Anytime I look at mirror I dey cap for myself
I go pass Micheal Jackson I know time go tell
Wọn le wọn o ba
Ẹru to jura wọn lọ
[Chorus]
Patek
Dia lọrun mi ọmọ oro n gazo lọ
Laye
Igbadun lo wun mi mi o wa ja ọmọ
Lalẹ
Lalẹ Satide mi o wa ni ṣọmọ
Adura mummy pọ gan-an lori mi ki mama jẹun ọmọ
[Chorus]
Patek
Dia lọrun mi ọmọ oro n gazo lọ
Laye
Igbadun lo wun mi mi o wa ja ọmọ
Lalẹ
Lalẹ Satide mi o wa ni ṣọmọ
Adura mummy pọ gan-an lori mi ki mama jẹun ọmọ
[Refrain]
Ki mama jẹun ọmọ
Ki mama jẹun ọmọ
Ki mama jẹun ọmọ
Adura mummy pọ gan-an lori mi ki mama jẹun ọmọ
[Verse 2]
E sure me say na country make am be like say everybody dey craze
Before you shook me shook yourself brother make you self see how the thing dey pain
If them fit allow me make I be the president of Naija for a day
Ma ṣọpẹ bi were
Ma ni k'ọn legalize igbo si orile-ede
[Verse 3]
Come show me your plug ko fa mi re ilu ọgbọn
Don’t wake me up un-til 4:20 on dot
O le ja Lambo ẹni tẹ ro pe ko le pagọ
Ṣe iwo o nigbagbọ
Abi ọja lo n parọ
[Chorus]
Patek
Dia lọrun mi ọmọ oro n gazo lọ
Laye
Igbadun lo wun mi mi o wa ja ọmọ
Lalẹ
Lalẹ Satide mi o wa ni ṣọmọ
Adura mummy pọ gan-an lori mi ki mama jẹun ọmọ
[Chorus]
Patek
Dia lọrun mi ọmọ oro n gazo lọ
Laye
Igbadun lo wun mi mi o wa ja ọmọ
Lalẹ
Lalẹ Satide mi o wa ni ṣọmọ
Adura mummy pọ gan-an lori mi ki mama jẹun ọmọ
[Refrain]
Ki mama jẹun ọmọ
Ki mama jẹun ọmọ
Ki mama jẹun ọmọ
Adura mummy pọ gan-an lori mi ki mama jẹun ọmọ
Written by: Adewale Atanda
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...