album cover
Asiko
2
Afro-Beat
Asiko was released on June 24, 2026 by 13050321 Records DK as a part of the album Omoluabi - EP
album cover
Release DateJune 24, 2026
Label13050321 Records DK
LanguageEnglish
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM

Credits

PERFORMING ARTISTS
AdeLeke
AdeLeke
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
AdeLeke
AdeLeke
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
AdeLeke
AdeLeke
Co-Producer

Lyrics

Asiko by Adeleke
Omo oloja ijumu
Toba ri je lo ni mase gberaga
Kosi eni to mole ti o mo lola
Edie ti o ku sile je agbado
Igba ti elode asiko temi nbo lona
Ki se pe nkan yan ori owo
Asiko mi ni ko ti to
Emi o ni wo ago alago sise
Oluwa lo mo ojo bukun mi
Ki se pe nkan yan ori owo
Asiko mi ni ko ti to
Emi o ni wo ago alago sise
Oluwa lo mo ojo igbega mi
Asiko mi ni ko ti to
Sugbon mo mo pe yio de
Asiko mi ni ko ti to
Ori mi o ni gbagbe mi
Asiko mi ni ko ti to
Sugbon mo mo pe yio de
Mo duro de aseda tori ileri re ki subu
Edie mi nlagun
Iyarare ni o je kan mo
Eleda mi amado yo
Ariwo re lo ma po
What will be will be
Momo o dami loju
Kirakita o dola o
Oluwa ni ko niyo
Momo akololo mi a pe baba
Gbogbo aye o gbo oruko mi
Mo fi gbogbo re le aseda lohun
Tori o ni kan lo mo jo
Ola mi
Mo mo akololo mi a pe baba
Ibukun mi o ro bi ojo a ro ma duro
Kosi eni to le daun ti Olorun se duro
Ayanmo mi se ni ojo re
E ma ba mi joyo (Ijoyo)
A ni e ma ba mi rere ayo
Omo ma de owo ma de
Igbe ga ma de laye
Asiko mi ni ko ti to
Sugbon mo mo pe yio de
Asiko mi ni ko ti to
Ori mi o ni gbagbe mi
Asiko mi ni ko ti to
Sugbon mo mo pe yio de
Mo duro de aseda tori ileri re ki subu
Toba ri jelo ni mase gberaga
Kosi eni to mole ti omo lola
Edie ti o ku sile je abado
Igba ti elode asiko temi nbo lona
Ayanmo mi yo se ni oruko oluwa
E ma ba mi joyo (Ijoyo)
A ni e ma ba mi rere ayo
Omo ma de owo ma de
Igbe ga ma de laye
E ma ba mi joyo (Ijoyo)
A ni e ma ba mi rere ayo
Omo ma de owo ma de
Igbe ga ma de laipe
Asiko ni gbogbo nkan
Owo mi mato kan
Lase aseda
Adeleke omo oloja ijumu
Written by: AdeLeke
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...