album cover

awade

18,753African2026
album cover
00:00
00:10
00:25
00:35
00:45
01:05
01:15
01:25
01:35
01:40
01:45
01:50
02:00
02:05
02:15
02:20
02:35
02:40
02:55
00:00
03:05
Past 7 Days
awade was discovered most frequently at around 1 minutes and 15 seconds into the song during the past week

Music Video

Music Video

Lyrics

[Intro]
Awa de, de de de de de, awa de
Awa la n gbe wọn debẹ, awa de o
Hm hm
Awa de, de de de de de, awa de
Ṣebi awa la n gbe wọn debẹ
[Verse 1]
Tori ki n le make ẹ ni mo ṣe sa nile
Ah, mo mọ po n gbohun mi from miles away
Ah, Yahwe, Yahwe jọ ba mi ṣe
To avoid the banter mo n calculate
[PreChorus]
Ah, mi o mọ oju ogun le n ba ti gbe bazooka
I saw some ṣege, aanu ṣa mo ri gba
So, ẹlẹda mi mo bẹbẹ
Nibi tọ'n wa mọto ki n ma lọ lo kẹkẹ
I for don die ọpẹlọpẹ EL Morija
[Chorus]
Awa de, de de de de de, awa de
Awa la n gbe wọn debẹ, awa de o
Hm hm
Awa de, de de de de de, awa de
Ṣebi awa la n gbe wọn debẹ
[Verse 2]
I don't know, I don't know
But mo n gbadura k'ọn ma ko mi jẹ bi Yakoyo
Ki oṣi yii ma ta mi bi tambolo, oh
Kọrin fun wọn bi Tony Tetuila, all I need is my own o
[PreChorus]
Ah, mi o mọ oju ogun le n ba ti gbe bazooka
I saw some ṣege, aanu ṣa mo ri gba
So, ẹlẹda mi mo bẹbẹ
Nibi tọ'n wa mọto ki n ma lọ lo kẹkẹ
I for don die ọpẹlọpẹ EL Morija
[Chorus]
Awa de, de de de de de, awa de
Awa la n gbe wọn debẹ, awa de o
Hm hm
Awa de, de de de de de, awa de
Ṣebi awa la n gbe wọn debẹ
[Outro]
Awa la n gbe wọn debẹ, awa de o
Ṣebi awa la n gbe wọn debẹ
Written by: Afolarin Odunlami, Kareem Temitayo Olasunkanmi, Oluwole Ebenezer

Shazam Footer

Select language:
Google Play Store
Apple App Store
Chrome Web Store
Galaxy Store

Follow Us

Loading...