Şarkı sözleri

A f'ope f'Olorun L'okan ati l'ohun wa Eni s'ohun 'yanu N'nu Eni t'araye n yo Gbat'a wa l'om'owo On na l'o ntoju wa O si f'ebun ife Se 'toju wa sibe Oba Onibuore Ma fi wa sile laelae Ayo ti ko l'opin On 'bukun y'o je ti wa Pa wa mo ninu oore To wa, gb'a ba damu Yo wa ninu ibi L'aye ati l'orun K'a f'iyin on ope F'Olorun, Baba, Omo Ati Emi mimo Ti o ga julo lorun Olorun kan laelae T'aye at'orun n bo Bee lo wa di isiyi Beeni yo wa laelae Eyo ninu Oluwa, e yo Eyin t'okan re se dede Eyin t'o ti yan Oluwa Le 'banuje at'aro lo E yo! E yo! E yo ninu Oluwa, e yo! E yo! E yo! E yo ninu Oluwa, e yo! E yo tor' On l'Oluwa L'aye ati l'orun pelu Oro Re bor' ohun gbogbo O l'agbara lati gbala E yo! E yo! E yo ninu Oluwa, e yo! E yo! E yo E yo ninu Oluwa, e yo! 'Gbat' a ba n ja ija rere Ti ota fere bori wa Ogun Olorun t'a ko ri Po ju awon ota wa lo E yo! E yo! E yo ninu Oluwa, e yo! E yo! E yo E yo ninu Oluwa, e yo! Okan mi n yo ninu Oluwa 'Tori O je iye fun mi Ohun Re dun pupo lati gbo Adun ni lati r'oju Re Emi n yo ninu Re Emi n yo ninu Re Gba gbogbo lo n fi ayo kun okan mi 'Tori emi n yo ninu Re O ti n wa mi pe ki n to mo O 'Gbati mo rin jina s'agbo O gbe mi wa sile l'apa Re Nibi ti papa tutu wa Emi n yo ninu Re Emi n yo ninu Re Gba gbogbo lo n fi ayo kun okan mi 'Tori emi nyo ninu Re Oore at'anu Re yi mi ka Or'ofe Re n san bi odo Emi Re n to, o si n se 'tunu O mba mi lo si 'bikibi Emi n yo ninu Re Emi n yo ninu Re Gba gbogbo lo n fi ayo kun okan mi 'Tori emi nyo ninu Re Iwo to fe wa la o ma sin titi Oluwa Oloore wa Iwo to nso wa ninu 'danwo aye Mimo logo Ola Re Baba, Iwo l'a o ma sin Baba, Iwo l'a o ma bo Iwo to fe wa l'a o ma sin titi Mimo l'ogo ola Re Iwo to f'agan l'omo to n pe ranse Ninu ola Re to ga Eni t'o ti s'alaileso si n dupe Fun 'se ogo ola Re Baba, Iwo l'a o ma sin Baba, Iwo l'a o ma bo Iwo to fe wa l'a o ma sin titi Mimo l'ogo ola Re Eni t'ebi n pa le ri ayo ninu Agbara nla Re to ga o Awon to ti n woju Re fun aanu Won tun n yo ninu ise Re Baba, Iwo l'a o ma sin Baba, Iwo l'a o ma bo Iwo to fe wa l'a o ma sin titi Mimo l'ogo ola Re Baba E se aanu Yin duro Baba E se o Baba E se o, aanu Yin duro Baba E se aanu Yin duro Baba E se Baba E se o Baba E se, aanu Yin duro Eyin ni o, Olorun o Eledumare, Oba ogo Eyin ni o, Olorun Awimayehun, Alagbara Eyin ni o, Olorun o Eledumare, Oga ogo Eyin ni o, Olorun o Awimayehun, Alagbara K'a to da aye, n'Iwo ti wa K'ole mi to so ninu iya mi, l'O ti n joba Olorun Baba o, Olorun omo Olorun Emi mimo Iwo n'ibere ohun gbogbo Iwo ni opin ohun gbogbo Awimayehun, Alagbara Eyin ni o, Olorun o Eledumare, Oga ogo Eyin ni o, Olorun o Awimayehun, Alagbara Oluwa orun on aye 'Wo n'iyin at'ope ye fun Bawo la ba ti fe O to! Onibu ore Orun ti n ran, at' afefe Gbogbo eweko n so 'fe Re 'Wo l'O n mu irugbin dara Onibu ore Onibu ore Bawo la ba ti fe O to! Onibu ore Fun ara lile wa gbogbo Fun gbogbo ibukun aye Awa yin O, a si dupe Onibu ore Fun idariji ese wa Ati fun ireti orun Ki l'ohun t'a ba fifun O Onibu ore Onibu ore Bawo la ba ti fe O to! Onibu ore O se mi laanu, ma a polongo Re Oba t'o se mi laanu, eh eh, ah ah Ma a polongo Re O se mi laanu, ma a polongo Re Oba t'o se mi laanu, eh eh, ah ah Ma a polongo Re Oju mi ti ri, eti mi ti gbo Enu mi ma soro n'pa ise Oluwa Oju mi ti ri o, eti mi ti gbo Enu mi ma soro n'pa ise Oluwa Oju mi ti ri, eti mi ti gbo Enu mi ma soro n'pa ise Oluwa Oju mi ti ri, eti mi ti gbo Enu mi ma soro n'pa ise Oluwa Olori ijo t'orun L'ayo l'a wole fun O K'O to de, ijo t'aye Y'o ma korin bi t'orun A gbe okan wa s'oke Ni 'reti t'o ni 'bukun Awa kigbe, awa f'iyin F'Olorun igbala wa Bi a wa ninu 'ponju T'a n koja ninu ina Orin ife l'awa yo ko Ti yo mu wa sun mo O Awa n sape, a si yo Ninu ojurere Re Ife t'o so wa di Tire Y'o pa wa mo titi lae Iwo mu awon eeyan Re Koja isan idanwo A k' yo beru wahala Tori O wa nitosi Aye, ese, at'Esu Koju 'ja si wa lasan L'agbara Re, a o segun A o si ko orin Mose Aribiti, Arabata Eyin l'atobiju Aribiti, Arabata Eyin l'atobiju Oluwa Oluwa, Eyin l'atobiju Aribiti, Arabata Eyin l'atobiju Aribiti, Arabata Eyin l'atobiju Oluwa Lat'ojo ti mo ti n rin Eh oh, eh eh eh eh oh Emi o ri 'ru Olorun eyi ri Eh oh, eh oh Lat'ojo ti mo ti n rin Eh oh, eh oh Emi o ri 'ru Olorun eyi ri Eh oh, eh oh Ojo nla l'ojo ti mo yan Olugbala l'Olorun mi O ye ki okan mi ma yo K'o si ro ihin na kale Ojo nla l'ojo na Ti Jesu we ese mi nu O ko mi ki n ma gbadura Ki n ma sora, ki n si ma yo Ojo nla l'ojo na Ti Jesu we ese mi nu Ise igbala pari na Emi di t'Oluwa mi loni ati lojo gbogbo Ohun l'o pe mi, ti mo si je o Mo f'ayo j'ipe mimo na Ojo nla l'ojo na Ti Jesu we ese mi nu O ko mi ki n ma gbadura Ki n ma sora, ki n si ma yo Ojo nla l'ojo na Ti Jesu we ese mi nu Eyin orun gbo eje mi, Eje mi ni ojojumo Emi y'o ma so dotun titi Iku yo fi mu mi rele Ojo nla l'ojo na Ti Jesu we ese mi nu O ko mi ki n ma gbadura Ki n ma sora, ki n si ma yo Ojo nla l'ojo na Ti Jesu we ese mi nu Gbese ope mi po, emi o le san tan Amo o sibesibe, ma a se 'won ti mo le se Baba Alaanu mi, E ma se o Baba Gbese ope mi po, emi o le san tan Amo o sibesibe, ma a se 'won ti mo le se Baba Alaanu mi, E ma se o Baba Mo n tesiwaju l'ona na Mo n goke sii lojojumo Mo n gbadura bi mo ti n lo Oluwa jo gbe mi soke Oluwa, jo gbe mi soke Fa mi lo si ibi giga Apata t'o ga ju mi lo Oluwa jo gbe mi soke Ife okan mi ko duro Laarin 'yemeji at'eru Awon miran le ma gbe be Ibi giga l'okan mi n fe Oluwa, jo gbe mi soke Fa mi lo si ibi giga Apata t'o ga ju mi lo Oluwa jo gbe mi soke Mo fe de 'bi giga julo Ninu ogo didan julo Mo n gbadura ki n le de be Oluwa mu mi de 'le na Oluwa, jo gbe mi soke Fa mi lo si ibi giga Apata t'o ga ju mi lo Oluwa jo gbe mi soke Igbagbo mi duro l'ori Eje at' ododo Jesu N ko je gbekele ohun kan Leyin oruko nla Jesu Mo duro le Kristi Apata Ile miran, iyanrin ni Mo duro le Kristi Apata Ile miran, iyanrin ni B'ire-ije mi tile gun Ore-ofe Re ko yi pada B'o ti wu ki iji na le to Idakoro mi ko niye Mo duro le Kristi Apata Ile miran, iyanrin ni Mo duro le Kristi Apata Ile miran, iyanrin ni Ore-ofe, ohun Adun ni l'eti wa Gbohun-gbohun re y'o gba orun kan Aye y'o gbo pelu Ore-Ofe sa N'igbekele mi Jesu ku fun araye O ku fun mi pelu Ore-Ofe to mi S'ona alaafia O n toju mi l'ojojumo Ni irin ajo mi Ore-Ofe sa N'igbekele mi Jesu ku fun araye O ku fun mi pelu Je k' ore-ofe yi F'agbara fokan mi Ki n le fi gbogbo ipa mi At' ojo mi fun O Ore-Ofe sa N'igbekele mi Jesu ku fun araye O ku fun mi pelu Ninu irin ajo mi, beeni mo n korin Mo n toka si Kalfari, nibi eje na Idanwo lode ninu, l'ota gbe dide Jesu l'O nto mi lo, isegun daju A! mo fe ri Jesu, ki n ma w' oju Re Ki n ma korin titi, nipa oore Re Ni ilu ogo ni, ki n gbohun soke Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi Ninu ise isin mi, b'okunkun ba su Un o tubo sunmo Jesu, y'O tan imole Esu le gb' ogun ti mi ki nle sa pada Jesu l'o nto mi lo, ko s'ewu fun mi A! mo fe ri Jesu, ki n ma w' oju Re Ki n ma korin titi, nipa oore Re Ni ilu ogo ni, ki n gbohun soke Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi Bi mo tile bo sinu afonifoji Imole itoni Re y'o mole si mi Y'o na owo Re si mi, y'O gbe mi soke Un o tesiwaju b'O ti n to mi lo Nigbati iji aye yi ba yi lu mi Mo ni abo t'o daju labe apa Re Y'O ma f'owo Re to mi titi de opin Ore ododo ni, A! mo ti f'E to A! mo fe ri Jesu, ki n ma w' oju Re Ki n ma korin titi, nipa oore Re Ni ilu ogo ni ki n gbohun soke Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi Nipa ife Olugbala Ki y'o si nkan Oju rere Re ki pada Ki y'o si nkan Owon l'eje t'o wo wa san Pipe l'edidi or'ofe Agbara l'owo t'o n gba ni Ko le si nkan Bi a wa ninu iponju Ki y'o si nkan Igbala kikun ni tiwa Ki y'o si nkan Igbekele Olorun dun Gbigbe ninu Kristi l'ere Emi si n so wa di mimo Ko le si nkan Ojo ola yio dara Ki y'o si nkan 'Gbagbo le korin ni 'ponju Ki y'o si nkan A gbekele 'fe Baba wa Jesu n fun wa l'ohun gbogbo Ni yiye tabi ni kiku Ko le si nkan Amin.
Writer(s): Sola Allyson Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out