Şarkı sözleri

We're making money, we're making money We're making money this year We're making money this year No matter what them do E go be better this year This year, this year, this year This year, this year, this year Ọdún yí, à sàn wá sí'rè À sàn wá s'ayọ À sàn wá sí gbogbo ń kan t'èyàn fí láàyò Mo lo má sàn wá sí'rè, a sàn wá s'ayọ À sàn wá sí gbogbo ń kan t'èyàn fí lá- This year, this year, this year Good money, new money this year This year, this year, this year This year, this year, this year À sàn wá sí'rè, à sàn wá s'ayọ À sàn wá sí gbogbo ń kan t'èyàn fí láàyò À sàn wá sí'rè, a sàn wá s'ayọ À sàn wá sí gbogbo ń kan t'èyàn fí láayọ À bí'mọ lé'mọ o, a má kọ'lé mọ'le o A rọ'kọ mọ 'kọ À bí'mọ lé'mọ o, a má kọ'lé mọ'le o A rọ'kọ mọ 'kọ Àlàáfíà tó pé, tó pé ye, to pe ye ní ilé mí Àlàáfíà tó pé, tó pé nílé gbogbo wa Àlàáfíà tó pé, to pe ye ní ilé mí Àlàáfíà tó pé, tó pé ye nílé gbogbo wa Torí ọdún eléyìí, ó má sàn wa si'rè Odẹ ma sàn wá s'ayọ À sàn wá sí gbogbo ń kan t'èyàn fí láàyò Mo lo má sàn wá sí'rè, a sàn wá s'ayọ À sàn wá sí gbogbo ń kan t'èyàn fí láàyò Ori burúkú back to sender láyé mí Air'owó na back to sender láyé mí Àìníṣẹ lọwọ back to sender láyé gbogbo wa, ah Air'owó na, aìníṣẹ lọ'wọ, ori burúkú back to sender This year, this year, this year This year, this year, this year We're making money, we're making money We're making money this year This year This year, this year, this year Listen, I'm making money I'm making money, I'm making money this year I don't care about you, I don't care what you think I don't care what you know But me, see, I'm making money, I'm making money I'm making money this year Me, I'm making money this year no matter what dem do Things go better, e go better, e go better this year
Writer(s): Raymond Lawrence Riley, Damion Gallegos Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out