Şarkı sözleri

(It's so easy) (Connecting slow) Ask about me, ask about me ('bout me) Wọn tí lé mí, but wọn mù mí (mu mí) Ọmọ Ọlọrun, kólé sú mí Seke-sekebula ('bula) I'm still getting my mula (mula) Dollar pẹlú naira (naira) Ikú tó pá ìyá teacher (teacher), ò lé pá àwọn nigga Kí ló ńfó lókè oh? (Fó lókè) Ẹyẹ ló ńfó lókè oh (fó lókè) Kí ló ń rìn ni'lẹ? (Rìn ni'lẹ) Àwọn èèyàn ló má ńrìn ni'lẹ, mà tẹ mí mọ'lẹ, oh-oh Má tẹ ojú ilẹ mọ'lẹ, kò máà bà dọbalẹ Ìwọ lómá f'Èkó lẹ, ko f'Èkó lẹ fún wá One man soldier, mẹta-mẹta, gbosa Awilo Logomba, fún mi l'owó mí biza Kese-kese, kasa, Casa-Casablanca I open Bible Chapter, I stepped on the Satan Mó p'èṣù dànù, mó kàn l'ẹsẹ kàn O tamurege, Jigan, oh-oh, why? Oh-oh, why? They don't know, they don't know They don't know, they don't know I don go (they don't know) They wan' know, they wan' know They wan' know, they wan' know where I'm going (I don go) Kí ló fà frapapapa? Kí ló fà pattern yẹn? Wọn fẹ ká mí mọ 'bẹyẹn Ọpọ́n tí sún finally, ọpọ́n tí sún finally À ò bà ẹlẹ́nu méjì ṣeré mọ Ask about me, ask about me ('bout me) Wọn tí lé mí, but wọn mù mí Ọmọ Ọlọrun, kólé sú mí Seke-sekebula ('bula) I'm still getting my mula (mula) Dollar pẹlú naira (naira) Ikú tó pá ìyá teacher (teacher), ò lé pá àwọn nigga Kí ló ńfó lókè o? (Fó lókè) Ẹyẹ ló ńfó lókè o (fó lókè) Kí ló ń rìn ni'lẹ? (Rìn ni'lẹ) Àwọn èèyàn ló má ńrìn ni'lẹ, mà tẹ mí mọ'lẹ, oh-oh Má tẹ ojú ilẹ mọ'lẹ, kò máà bà dọbalẹ Ìwọ lómá f'Èkó lẹ, ko f'Èkó lẹ fún wá One man soldier, mẹta-mẹta, gbosa Awilo Logomba, fún mi l'owó mí biza Kese-kese, kasa, Casa-Casablanca I open Bible Chapter, I stepped on the Satan Mó p'èṣù dànù, mó kàn l'ẹsẹ kàn O tamurege, Jigan, oh-oh, why? Oh-oh, why?
Writer(s): Noble Zogli, Ilerioluwa Oladimeji Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out