Şarkı sözleri

K'atọ to dọmọ lo tí mọ mí O pe mi L'eyinju uuu Kí n to dọmọ lo tí mọ ohun maa da o Ogo fún ẹni to dami K'atọ to dọmọ lo tí mọ mí O pe mi L'eyinju uuu Kí n to dọmọ lo tí mọ ohun maa da o Ogo fún ẹni to dami Eweko kò ni Jabo Kọ sẹhin Olodumare Òhun ti mo máà dà ti mo n da lọwọ O ti wa ninu eto óo bàbá ooo Eleda tó dá mi O ma ṣe eee ooo K'ẹjẹ to dọmọ lo tí mọ mi O pe mi L'eyinju uuu Kí n to dọmọ lo tí mọ ohun maa da o Ogo fún ẹni to dami Eto Ọlọrun ni mi Ẹda ayé o le pe mi lasiṣe Ninu eto Ọlọrun ni mo wa Eyi ló fí f'ẹtọ fún mí Ẹtọ èyí l'ogo to ṣe mi yatọ A o ko dami gan lasan O ni a dami ni ìrì oun And he took it personal O pe mi ní ògo, ọla, ire Ọrọ ibukun rẹpẹtẹ E yíì ṣa l'ẹri ifẹ Oluwa simiii pẹ K'atọ to dọmọ lo tí mọ mí O pe mi L'eyinju uuu Kí n to dọmọ lo tí mọ ohun maa da o Ogo fún ẹni to dami K'ẹda ayé máa sáré òhun to wá leto Mi o ni duro sùgbón ma kanju Ma dẹ sáré asa ju laye Ẹlẹtọ ni iṣẹda kò ni rẹ' ọ jẹ O wa ninu eto o Ẹtọ a tẹ ọ lọwọ O ti mọmi ooo ka to dami sinu Kí n to tinu Jade lo tí sọ mi di mímọ Aya mi s'ọtọ ọọ Ayé mi n bọla fún ìdá ti o lasiṣe Peki ni ire n ṣere lọdọ emi Eyinju baba O f'ogo fún ùn O f'ola fun O f'ogo fún ùn O f'ola fun K'ẹjẹ to dọmọ lo tí mọ mi O pe mi L'eyinju uuu Kí n to dọmọ lo tí mọ ohun maa da o Ogo fún ẹni to dami
Writer(s): Nifemi David Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out