album cover
Prayer
787
Big Band
Prayer adlı parça {albumName} albümünün bir parçası olarak Bhadmanyankee tarafından 9 Ocak 2026 tarihinde yayınlandıPrayer - Single
album cover
Çıkış Tarihi9 Ocak 2026
FirmaBhadmanyankee
DilEnglish
Melodiklik
Akustiklik
Valence
Dans Edilebilirlik
Enerji

Krediler

PERFORMING ARTISTS
Agbotifayo Empire Music
Agbotifayo Empire Music
Basset Horn
COMPOSITION & LYRICS
Agbotifayo Empire Music
Agbotifayo Empire Music
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Afolabi
Afolabi
Engineer

Şarkı sözleri

Ifa ni kagbogun gbodun kamalee dele ologun
Ka gbogbote kama lee dele olote
Agbonlukere asubu lu ote maku
Omo Awo kiiku Sipo ologberi
Ole kii jagba koma kofiri
Ojo ti eba ri afefe mu ni ki eto rimi mu
Difa fun orunmila
Lojo tiwon ndoju ibi metaa ko baba
Won ni ki baba ko sinwin wogbo
Won ni ki orunmila ko ya were kowogbe
Won ni ki baba komaa pon laso bi ibepe
Ifa ni toba se bi ise toun ni
Ela biise temi ni bari agbonmiregun
Ifa ni emi koni siwin wogbo laelae
Emi oni yawerewogbe
Emi koni bawon pon laso bi ibepe
Oni ata kiipon ki igire tunnaapon
Eewo,Ifa maje kin ri iponju nile ayeetemi
Orogbo ningbomo sile aye
Obi ninbi gbogbo ibi sorun morere
Ewa fi obi bi gbogbo ibi araami sorun morere
Enu ti adan finje ni adan finpo
Egunyin koleeranmimo o
Epe yin kolee ranmimo o
Ojo ti oloti bamu oti nintoo danu
Ojo ti eleko bamu eko nintodanu
Ero nitigbin
Igbin kii gbenu ikarawun ko siwin
Ero ni ti alabawun
Alabawun koni gbe inu igbare ko sierra
Ero ni tadan
Ninu egbe ladan nroosi
Ata ni ko ta gbogbo ibi kuro laraami
Ikabara IFA kio wa kawo ibi kuro laraami loni dandandan.
Written by: Agbotifayo Empire Music
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...