制作
出演艺人
Beautiful Nubia
表演者
作曲和作词
Olusegun Akinsete Akinlolu
词曲作者
歌词
Ole f'airo'ko f'aiko'be, o mi reti owo
L'aide'le f'oka, t'ebu bo'le, o nru'bo ojo
Onifakafiki-fikifaka l'ori iro
Yio ba ni'be ó, ofo l'o ma ba
Sebi oun t'a ba gbin l'aye, oun l'a ma ka
Ko ba won d'oja, ba won na'ja, o nlogun ota
Oniwuruwuru, agb'ona Abuja, af'erud'oloro
Ko ba won d'oko, ba won d'odo, o ns'oro ikore
Yi o ba ni'be, ofo l'o ma ba
Se bí oun t'a ba gbin l'aye, oun l'a ma ka
Ojo nlo kia, asiko o duro, ma s'ole
Enikan o pe titi ko lo'le aye gbo o
Eni ńṣe ranlowo, fa'nis'oke, ko ni s'alaini
Onirele okan, abowof'agba, yio pe ni'le
Bo ku die k'eni're jin s'ogbun, igbala a yo de
Yio ba ni'be, ire l'o ma ba
Se bí oun t'a ba gbin l'aye, oun l'a ma ka
Jowo s'oro iwuri, oro rere, f'eni t'o nsa're
Ka ma f'iwa ilara at'aimora f'owo ago s'ehin
Eni nja'ja rere at'ominira, ka gbe won duro
Ka le ba ni'be, ire l'a ma ba
Se bí oun t'a ba gbin laye - oun l'a ma ka
Ile aye, af'oba fi'le ni
Enikan o pe titi ko lo'le aye gbo o
Written by: Olusegun Akinsete Akinlolu

