歌词

Iya, Iya ta'kun wa'le- Alujanjankijan Iya, Iya ta'kun wa'le- Alujanjankijan E ma f'omo s'ile fun'ya je- Alujanjankijan Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo- Alujanjankijan (VERSE 1- Sola Allyson) Ba mi n'omo mi, o ye k'o de'nu olomo Oju merin lo n bi'mo, sugbon, igba oju li n w'omo Omo t'a o ko, a gbe'le t'a ko ta Omo t'a o to, a k'eso t'a ni ta Omo n'igbeyin, omo l'ola, omo l'ola, omo n'iyi, omo l'ade Omo l'ewa, omo l'eso oh ohhh O da a, bi o da a- o le da a; o san, bi o san- a de san Igboya at'adura ni o gba- yi o da ahhh (Sola Allyson- CHORUS) Iya, Iya ta'kun wa'le- Alujanjankijan Iya, Iya ta'kun wa'le- Alujanjankijan E ma f'omo s'ile fun'ya je- Alujanjankijan Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo e; e t'omo- Alujanjankijan (VERSE 2- Adekunle Gold) Ori fun wa l'omo're bi i ti Samuel oh Won ko Samu, o gb'eko oh, o si se'hun rere If you spare the rod, you go spoil the child; I hope you know? Train them with the love of God; abegi oh Tori, alaigboran omo- asa ni Agba o kunwo l'oju- asa ni Agba o jo won l'oju oh- asa ni Agba iya ni o da- asa ni Alalugboran omo oh- omo ni Won le d'eyan l'ola- omo ni T'a ba to won daada o- omo ni Won le d'eyan l'ola (Adekunle Gold- CHORUS) Iya, Iya ta'kun wa'le oh- Alujanjankijan Iya, Iya ta'kun wa'le oh- Alujanjankijan Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo oh- Alujanjankijan E ma f'omo s'ile fun'ya je oh- Alujanjankijan (CHORUS- Sola Allyson) Iya, Iya ta'kun wa'le oh ohh- Alujanjankijan E ma f'omo s'ile fun'ya je ohh- Alujanjankijan Eni t'o bi'mo e lo ye k'o w'omo e; e t'omo- Alujanjankijan Iya, baba, t'akun wa'le- Alujanjankijan
Writer(s): Writer Unknown, Adekunle Kosoko Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out