音乐视频

Asa - Grateful (Official audio)
观看 {artistName} 的 {trackName} 音乐视频

精选于

制作

出演艺人
Aṣa
Aṣa
表演者
作曲和作词
Bukola Elemide
Bukola Elemide
词曲作者
Greg Beker
Greg Beker
词曲作者
Michael Davey
Michael Davey
词曲作者

歌词

Era ilẹ', era ilẹ', wọn yìn Bàbá l'òkè 'Yanrìn, òkun, 'yanrìn, òkun, wọn yìn Bàbá l'òkè Ẹranko ilé, ẹranko igbó, wọn yín Bàbá l'òkè Àwọn aláìní, àwọn tán tí ní, wọn yìn Bàbá l'òkè Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe'yán Kò tó mọ pé Bàbá ń bẹ l'òkè Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe'yán Kò tó mọ pé loótọ' ò ńbẹ l'òkè You don't have to wait 'til you feel the pain You can start right now It's not too late It's not too late to be grateful! Ah, ah, uhm Ah, ah, ah, ah-ah, ah Hmm-mmm Era ilẹ', era ilẹ', wọn yìn Bàbá l'òkè 'Yanrìn òkun, 'yanrìn òkun, wọn yìn Bàbá l'òkè Pé mo wà láyé, mo wà láàyè Gbogbo òun tí mò ní, má fí yìn ò lógo Believe this world a better place Ah-ah-ah, eh-eh Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe'yàn Kò tó mọ pé Bàbá ńbẹ l'òkè (okay) Kò ṣe ìgbátí ńkán bà ṣe'yàn Kò tó mọ pé loótọ' ò ńbẹ l'òkè You don't have to wait 'til you feel the pain You can start right now (okay) It's not too late (it's not too late) It's not too late to be grateful (yes) Ahh O rí bí mo ṣe ńf'ẹgbẹ yìn Bàbá Ta, du-ba, du-ba (hey) Ta, du-ba, du-bu (hey) Ba, du-ba, du-ba (hey) Da, du-da, du-bu (hey) It's not too late Uhh-uh-uh, eh (hey) Ta, du-ba, du-bu (Yeah-yeah, oh, that's right)
Writer(s): Greg Becker, Bukola Elemide, Michael Davey Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out