album cover
Ayedun
27,065
World
Ayedun 由 YBBM 于 2020年11月26日 发行,作为专辑“Alagbe”的一部分。
album cover
专辑Alagbe
发行日期2020年11月26日
唱片公司YBBM
旋律性
不插电
Valence
舞蹈性
能量
BPM100

音乐视频

音乐视频

制作

歌词

[Intro]
Seribumi
Seribumi elede kewu (Shocker lo ṣe beat)
Iji ra
Qdot lorukọ t'emi
Qdot lorukọ mi oh, eh-oh
[Verse 1]
Aye la bowo (Aye la bowo)
Aye la ma fi silẹ lọ (Silẹ lọ)
Ayanmọ pẹlu kadara wọn yatọ sira wọn
O ni kaja ma gbe nile, o yan kinihun sinu igbo
[PreChorus]
To ba lowo lo d'awo ile-aye (Yeah oh, e eh-eh)
O lowo lọwọ o d'ẹru aye (Ahn-ahn, ki lo de?)
Olowo l'aye ma fun laye, tori olowo l'aye fẹ ri
Ẹlẹdaa mi oh ṣe mi lẹni aye fẹ ri (Ẹlẹdaa mi oh-ohh)
[Chorus]
Eromi to n jo, to n jo lori omi
Eromi to n jo, to n jo lori omi
Ẹni lulu fun n bẹ nisalẹ odo, ṣebi Ọlọhun lo ba mi ṣe, yay
Eromi to n jo, to n jo lori omi
Ẹni lulu fun n bẹ nisalẹ odo, ṣebi Ọlọhun lo ba mi ṣe
Eromi to n jo, to n jo lori omi
[Verse 2]
Ọrẹ
Owo la fi n ṣe ile-aye
Iwa l'ọn ma fi n ṣọrun
Bo ṣe lowo to, lo ma gbadun oyinbo to
Lo mu Davido ọmọ baba olowo pariwo pe 'owo ni koko'
Money good ohh, ohh
Poverty no sweet oh, my brother
[PreChorus]
To ba lowo lo d'awo ile-aye (Ooh, ooh, yeah-yeah-yeah)
O lowo lọwọ o d'ẹru aye (Ahn-ahn ki lo de oh)
Olowo l'aye ma fun laye, tori olowo l'aye fẹ ri
Ẹlẹdaa mi oh, ṣe mi lẹni aye fẹ ri
[Chorus]
Eromi to n jo, to n jo lori omi (Ayy-ayy, oh)
Eromi to n jo, to n jo lori omi
Ẹni lulu fun n bẹ nisalẹ odo, ṣebi Ọlọhun lo ba mi ṣe
Eromi to n jo, to n jo lori omi
Ẹni lulu fun n bẹ nisalẹ odo, ṣebi Ọlọhun lo ba mi ṣe
Eromi to n jo, to n jo lori omi
[Verse 3]
Ayedun
(Aye dun jẹ ju'ya lọ)
Aye yii dun
(Aye dun jẹ ju'ya lọ)
Ori ṣe mi l'olowo aye
(Aye dun jẹ ju'ya lọ)
Bi ti Wasiu Ayinde oh
(Aye dun jẹ ju'ya lọ)
Bi ti K1 De Ultimate
(Aye dun jẹ ju'ya lọ)
Shout out to Mayegun gbogbo ilẹ Yoruba
[Outro]
Yeah, who's here?
Written by: Fakoya Oluwadamilare, Mudashiru Olajide
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...