歌词
Eyin ara Ibadan
Nibo ni aye wa?
Eyin ara ibadan
Nibo lo n selense
Mo so ni challenge
Ki n to gba bodija lo
Won ni ki n get ready
Won ni wa se toju mi ye!
Jejely mo n ja ye mi
Okan mi fo fayo
Won gbemi da agbowo
Mo le jeran alawo
Emi ma duro sibadan
Emi o lo le mo
Gele ti mo wo Ibadan
Ibadan di le mi
Emi ma duro sibadan
Emi o lo le mo
Gele ti mo wo ibadan
Ibadan di ile mi
Fast forward
Two years ti mo ti ko de Ibadan
Mo ti ri fine babes
Premium girls, ko n se lasan
Mo sowo, mo jere
Mo tun fowo ranse lo
Mo sowo mo jere
Mo tun sa owo igbadun jo
Emi ma duro sibadan
Emi o lo le mo
Gele ti mo wo ibadan
Ibadan di ile mi
Ani ma duro si ibadan
Emi o lo le mo
Gele ti mo wo Ibadan
Ibadan di ile mi
Eyin back up singers mi
E wa ba mi korin yo yo yo
Awa ma duro si ibadan
Awa o lo le mo
Gele ti a wo ibadan
Ibadan di ile wa
Ooh!!! Ahhh!! Opo!!!
Don’t kill my vibe
Don’t kill my vibe
No, you can’t kill our vibe
We’re phenomenal
We’re phenomenal
Phenomenal musician!!!
Written by: Adeniyi Timilehin