歌词
[Intro]
(Yo D')
[Verse 1]
Quality over quantity (O pree)
O ò mọrú ẹ, ṣọ ọ ní 'rú ẹ?
Ẹjẹblejẹ, ẹ'jẹ ló ń lò, oh no
Ọmọ tó ní ìyá òun ò ní sùn, ohùn gan-an gan-an ò ní sinmi
And as I dey tẹpá mọ my hustle, ẹ fún Adekunle mi ní Simi
Ara la mọ, ara la mọ (La mọ), a ò mọ ẹni tó fẹ' ni dénú
Àbí ẹ ò rí aṣinú, ó fi Bíbélì ka kéwú
Ara la mọ, ara la mọ (La mọ), a ò mọ ẹni tó fẹ ni dénú
Àbí ẹ ò rí aṣinú, ó fẹ fi Bíbélì ka kéwú
[Chorus]
Confirm ni, no be para oh
Control, no be galala
To make money, no be by dragger
Oh-oh-oh, a ya-ya
Confirm ni, no be paara oh
Control, no be galala
To make money, no be by dragger
Oh-oh-oh, a ya-ya (A ya-ya)
[Bridge]
Heys, ọmọ tó bá ta féleféle, ẹ gbá ojú ẹ
Ẹ le pa (Ẹ le pa), ó le kwa (ó le kwa), oh-uh-oh
Ọmọ tó bá bẹ sí mi, é è ní fara ire lọ
A jurawa lọ, ti ìjàkadì kọ, ìwọ náà mọ
[Verse 2]
Ẹni bínú mi, ò ní ní sinmi
Ẹ'yin enemies, kakulu fuhi
Yes, I mean dede yín
Mo sorry fún gbogbo yín oh-oh
Mo sorry fún gbogbo yín lọkọọkan
[Chorus]
Confirm ni, no be para oh
Control, no be galala
To make money, no be by dragger
Oh-oh-oh, a ya-ya
Confirm ni, no be paara oh
Control, no be galala
To make money, no be by dragger
Oh-oh-oh, a ya-ya
[Outro]
Heys, ọmọ tó bá ta féle-féle, ẹ gbá ojú ẹ
Ẹ le pa, ó le kwa
Ọmọ tó bá bẹ sí mi, é è ní fara ire lọ
A jurawa lọ, ti ìjàkadì kọ, ìwọ náà mọ
Written by: Barry Jhay
