制作
出演艺人
Kent Edunjobi
表演者
Otedola Oredolapo
吉他
David Peter
鼓
Gbenga Igiowo
低音吉他
Id Cabasa
管弦乐队
sesan odumosu
人声鼓
作曲和作词
Kent Edunjobi
词曲作者
歌词
Lv:
Ore ope l’emi muwa,
Ore re o po jaburata,
Ko de se simi, gege bi ti iwa mi,
Aanu ni mo ri gba lowo olorun mi
Chrs:
Ore ope l’awa muwa,
Ore re o po jaburata,
Ko se siwa, gege bi ti iwa wa,
Aanu la ri gba lowo olorun wa
Lv:
Opo l’ore ta o foju ri
Ko s’eni, t’olu o fi’re fun,
Chrs
Af’eni to b ani tire oto
Aanu la ri gba lowo olorun wa
Lv:
Opo l’ore ta o foju ri
Resp:
T’a o foju ri, Ah, ah
Lv:
Ko s’eni, t’olu o fi’re fun,
Af’eni to b ani tire oto
Aanu la ri gba lowo olorun wa
Chrs:
A e o, Ijinle ife t’oni siwa
Lafi nyan, fanda fanda 2ce
Chrs:
Ose eleru niyin a m’ope wa wa
A dupe onile ayo, tewo gb’ope wa
Ose eleru niyin a m’ope wa wa
A dupe onile ayo, tewo gb’ope wa
Elenkule adewure, oni’sun ayo wa
T’ewo gbope ti a muwa
T’ewo gbope ti a mu wa (till fade)
Written by: Kent Edunjobi