制作

出演艺人
Pasuma
Pasuma
表演者
作曲和作词
Pasuma
Pasuma
词曲作者
制作和工程
Bejiwa olugbemi
Bejiwa olugbemi
制作人
Omoola jamiu
Omoola jamiu
制作人
Diran Adedeji
Diran Adedeji
制作人
Elegun Akeem
Elegun Akeem
混音工程师

歌词

Ireje o si ninu aworon, Ireje o si ninu aworon
Toba shey joko loma ba ara e lojo ti foto e bama jade
(CHORUS)
Ireje Osi ninu aworon, toba Shey Joko loma ba ara e lojo ti foto e bama jade) x2
O sha Igi logbe, o ta oguro lofa seh o
O sha Igi logbe, o ta oguro lofa seh o
O de idi ope o lanu ton lagbari
Shoro pe ofe lemu n ro ni ise takun-takun ni agun ope n shey
Ireje Osi ninu aworon, toba Shey Joko loma ba ara e lojo ti foto e bama jade
Woni ko ka iwe o oni iyen o shey koko
Ko'ko ise o kor o oni oun o le ko ise
Wonpe alaru o ko dawon loun o tori bonu o
Ireje Osi ninu aworon, toba Shey Joko loma ba ara e lojo ti foto e bama jade
Shori Eni gbin efo toka agbado ri
Abi ori Eni gbin ewa to ko ere ila
Ko possible o o le je nibi ti o Shey si
Oun toba Shey nio ogba o advice mi re te pka mo ise
Ireje Osi ninu aworon, toba Shey Joko loma ba ara e lojo ti foto e bama jade
That is to say o ko jara mo ise x2
Akoko o duro feni kan rara x2
Gbe igbese kia kole ba to egbe x2
Tori oun taba sise fun lole pe lowo x2
Eyi tia sise fun koma kin tojo x2
Ireje Osi ninu aworon, toba Shey Joko loma ba ara e lojo ti foto e bama jade
Mofe komu kuro loro e (ore)
Ani komu kuro loro e o (padi)
Oro kole bosi kole shey shey
(Mejeji lon da eja laamu o nioje ko le gbinYanju) x2
Bi'oni showo tonlo si Oja toni toun ba de oja n je Aje mawa (oro noonu)
Ofe losi embassy fun interview o moju Aje ko oni iso oti fema fur (oro noonu)
Baba Wasila Alabi Ajibola o
Iwo tofe gba contract woni ero po lori e Oti wa relent pe shoma bosi sha (oro noonu)
Igbiyanju o lon shey atokun ola o
Igniyanju lon shey atokun ola o
Ore tepa mo ise kole dara fun E x2
Written by: Alh. Wasiu Alabi Pasuma
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...