制作
出演艺人
Kenny Peters
表演者
作曲和作词
Olayiwola Kehinde Peter
词曲作者
歌词
Mio ni ya alaimore,
Emi o ni ya alaimore,
Gbogbo igba lon sha toju mi,
Otun keh mi bi omo ikoko,
Certificate mi gan gan o le shey,
Nipa mimo yan mio ma mo yan rara,
Iwo lolumo to da oluran lowo,
Iba re ma re oo baba,
Mio ni ya alaimore,
Emi o ni ya alaimore,
Gbogbo igba lon sha toju mi,
Otun keh mi bi omo ikoko,
Certificate mi gan gan o le shey,
Nipa mimo yan mio ma mo yan rara,
Iwo lolumo to da oluran lowo,
Iba re ma re oo baba,
Mio ni ya alaimore,
Emi o ni ya alaimore,
Gbogbo igba lon toju mi,
Otun keh mi bi omo ikoko,
Certificate mi gan gan o le shey,
Nipa mimo yan mio ma mo yan rara,
Iwo lolumo to da oluran lowo,
Iba re ma re oo baba,
Iba re ma re oo olodumare,
(Iba re ma re oo baba),
Oba adani ma gbagbe eni,
(Iba re ma re oo baba),
Oba tio mo eni toju nkan,
Eni to ba kan lo ma dalohun,
(Iba re ma re oo baba),
Oba afuni ma siregun,
Oba alaanu, (Iba re ma re oo baba)
Mo more Mo More,
Mo more o olorun,
Otise Otise,
Baba mi loke Otise,
Mo more Mo More,
Mo more o olorun,
Otise Otise,
Baba mi loke Otise,
Mo more Mo More,
Mo more o olorun,
Otise Otise,
Baba mi loke Otise,
Mo more Mo More,
Mo more o olorun,
Otise Otise,
Baba mi loke Otise,
Mo more Mo More,
Mo more o olorun,
Otise Otise,
Baba mi loke Otise.
Written by: Olayiwola Kehinde Peter