制作
出演艺人
DOTTi The Deity
表演者
作曲和作词
Oladotun Alani Okeowo
作曲
制作和工程
Phleksibu
制作人
歌词
Nigba tiwọ o ba li Okun mọ
Baby Sinmi lemi
Nigba tiwọ o ba lalabaro
Baby sinmi lemi
Oh oh oh Maberu o
Asọ o ni bọ Lara re
Ebemi lejika re
Oh oh oh Mafoya o
Asọ o ni ye lọrun re
Ebemi lejika re
Nigba tiwọ
Ba yomije loju
Baby Sinmilemi o
Written by: Oladotun Alani Okeowo

