制作

出演艺人
Kizz Daniel
Kizz Daniel
声乐
Adekunle Gold
Adekunle Gold
声乐
作曲和作词
Adekunle Kosoko
Adekunle Kosoko
词曲作者
Anidugbe Oluwatobiloba
Anidugbe Oluwatobiloba
词曲作者
制作和工程
Philkeys
Philkeys
制作人
BlaiseBeatz
BlaiseBeatz
制作人
Reward Beatz
Reward Beatz
制作人
Vtek
Vtek
混音工程师
Anidugbe Oluwatobiloba
Anidugbe Oluwatobiloba
录音工程师

歌词

[Intro]
Vado
Wo, woba
Banger
[PreChorus]
K'Oluwa gbe wa gẹgẹ o
K'aye ma fi wa ṣẹfẹ
Ki n ra mọto ki n ma f'ẹsẹ ṣa
K'ọla mi de, k'ọla mi pọ ṣa
T'aye ba gbe ẹ leke
Wọn tun ma gbe ẹ ṣepe (Ọlọhun)
Ọmọ gutter to n fly by jet
Ice water lo n pa ongbẹ
[Chorus]
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun n tanna
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun n ṣana si o Vado
Ọla Oluwa ni (Ọla Ọlọrun ni o)
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun n tanna
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun n ṣana si o Vado
Ọla Oluwa ni
[Verse 1]
Blessings follow me differently
O yatọ s'awọn t'ẹlomi
After many many hit
After destinambari
Don't want your validation flower
I be who I say I am, Vado
I no dey fancy the life style
I just want sing f'awọn fans wa
I have ideas, plenty ideas, plenty ideas
I no dey fancy the life style, I just want sing
[PreChorus]
K'Oluwa gbe wa gẹgẹ o
K'aye ma fi wa ṣẹfẹ
Ki n ra mọto ki n ma f'ẹsẹ ṣa
K'ọla mi de, k'ọla mi pọ ṣa
T'aye ba gbe ẹ leke
Wọn tun ma gbe ẹ ṣepe (Ọlọhun)
Ọmọ gutter to n fly by jet
Ice water lo n pa ongbẹ
[Chorus]
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun n tanna
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun n ṣana si o Vado
Ọla Oluwa ni (Ọla Ọlọrun ni o)
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun n tanna
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun n ṣana si o Vado
Ọla Oluwa ni
[Verse 2]
Ta, ta, ta mẹtẹẹta ma ma jẹ o ba wa
Tale, toko pẹlu mọto
Hallelu, Hallelujah, Hossana
Ọmọ ọjọ yẹn di somebody
Pic, picture this I'm not perfect
But I'm still ten over ten
I'm God's favorite, I'm blessed
Applaudise, I came I saw
Shutdown when I enter the bar
Only big ballers in my corner
Odogwu ri mi o ni "kedu"
Big fish o ya drop the gbẹdu
Another day day, another dollar
From night fall titi d'ọla
The money long long plenty comma
Ko ni bajẹ o, abba father o
[PreChorus]
K'Oluwa gbe wa gẹgẹ o
K'aye ma fi wa ṣẹfẹ
Ki n ra mọto ki n ma f'ẹsẹ ṣa
K'ọla mi de, k'ọla mi pọ ṣa
T'aye ba gbe ẹ leke
Wọn tun ma gbe ẹ ṣepe (Ọlọhun)
Ọmọ gutter to n fly by jet
Ice water lo n pa ongbẹ
[Chorus]
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun n tanna
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun n ṣana si o Vado
Ọla Oluwa ni
[Outro]
Blood and sweat, ohh wee
Blood and tears la fi n ṣiṣẹ pawo
And the rich is preaching
Priest is freezing (Banger)
Temperature is very low
Written by: Adekunle Kosoko, Adewale Adeola, Anidugbe Oluwatobiloba Daniel, Marcel Akunwata, Philip Ahaiwe (Philkeyz)
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...