音乐视频

音乐视频

制作

出演艺人
Ayo Maff
Ayo Maff
领唱
Diamond Jimma
Diamond Jimma
领唱
作曲和作词
Abatan Enioluwa Olumide
Abatan Enioluwa Olumide
作曲
AYORINDE AYODELE MAFOLUKU
AYORINDE AYODELE MAFOLUKU
作曲
Adisa Oluwatomi King
Adisa Oluwatomi King
作曲
Juju the Pen
Juju the Pen
作曲
制作和工程
PS10
PS10
制作人

歌词

[Intro]
Ayo, Ayo Maff
[Verse 1]
Ọna lo jin, ọna lo jin ẹru ni baba
Ọmọ oro mi, ọmọ oro mi, client maa sanwo
N'gba ta ba le tẹra mo hustle yii say won ma sanwo
Ọmọ oro mi, ọmọ oro mi, no give up my padi
Duro ti mi Shade, duro ti mi Shade
Duro ti mi lalẹ yii, a duro ti mi Shade o
Omije loju mi my padi
I go school mi o le pari
And no be say I no sabi
But owo lo mi ṣojoro
Mumsy mi o le sọrọ mọ
My popsy no fit para
Ọmọ boy ti n fa kpoli
Ọmọ boy ti n mu gbo o
[Chorus]
Tori ko sowo ni ile (Eh ehh eh eh eh eh)
Ko sowo ni ile eh (Ko sowo nile o)
Tori ko sowo ni ile (Eh ehh eh eh eh eh)
Ko sowo ni ile eh (Ko sowo nile o)
[Verse 2]
Jama jama Jama
Cause ole lo bọmọ jẹ
Gbowo ka fa cana
Ase o le jo Micheal Jackson
Jama jama Jama
Ọmọ oro ma kana finishing
Jama Jama Jama
Ole lo bọmọ jẹ
[Verse 3]
Ah igboro o rẹrin-in
Aye o fẹni fọrọ
Ko n ṣebi la ma ku si
Ko n ṣebi la ma ku si
So I tie my worries for backwood
I smoke the pain away
Iyo iyo iyo iyo iyo
[Chorus]
Tori ko sowo ni ile (Eh ehh eh eh eh eh)
Ko sowo ni ile eh (Ko sowo nile o)
Tori ko sowo ni ile (Eh ehh eh eh eh eh)
Ko sowo ni ile eh (Oh oh, oh oh oh)
[Verse 4]
Mo wo yika ko seeyan kan
Bi mo ṣubu mo ni igbagbọ
Mi o ni fọmọ ṣeja once upon the story long
Ọmọ ọlọna sunta mi o rẹni fọrọ lọ
Ṣugbon mo mọ ibi mo n lọ
Ani kori ko mi yọ
Ara lo kan mi mo ṣe sa n'le
Oju mi o le gba iwọsi
Mo ṣe jama jama lọ
Ani kori ko mi yọ
Oṣi o yẹ mi
Wa ṣe wonder ti n ri ri
Ma fohun ti mi o fẹ dan mi wo
Ọna lo jin ọmọ ẹru naa ni baba
Iya o yẹ mi o, se wonder ti n ri ri
Ma fohun ti mi o fẹ dan mi wo
Written by: AYORINDE AYODELE MAFOLUKU, Abatan Enioluwa Olumide, Adisa Oluwatomi King, Juju the Pen, OLUMIDE OLUWAMAYOWA OYEFESO
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...