歌词

Bi e ba n gbo t'omode n ge 'gi ni 'gbo Agba lo le mo 'bi to mi a wo si B'omode ba rin irin ajo loju agba O le ma ba agba mo ni'le to ba de o Irin ajo eda laye, Olorun lo mo Opin irin ajo k'a fi s'adura Opin irin ajo temi tire ninu aye Oba je ko san wa o k'a jagunmolu Ti e ba n gbo Bi e ba n gbo t'omode n ge 'gi ni 'gbo Agba lo le mo 'bi to mi a wo si B'omode ba rin irin ajo loju agba O le ma ba agba mo ni'le to ba de o Irin ajo eda laye, Olorun lo mo Opin irin ajo k'a fi s'adura Opin irin ajo temi tire ninu aye Oba je ko san wa o k'a jagunmolu Opin irin ajo, oo— laye Abalo, ababo wa ninu aye Laisi laala ko ma si isinmi Eni to maa yege o, a rin un wi O fe lowo, o fe ko'le o ninu aye Laisi 'ranwo Olorun ofo lo ma ja si Eni fe se rere o, dandan a w'oju Olorun Esu o ni fun o lookan, ko ma fi gb'eedegbaa Ona eburu lonitohun yen a fi parun (a pa run ni) Opin irin ajo temi tire ninu aye Oba je ko san wa o, ka jagunmolu Laala ninu aye, irin ajo aye Ogun to n ja, t'Olorun nse won a re koja lo Opin irin ajo ni'ku, a gbe ni ju langba si koto Eni ti ku ni'sinmi, iyen p'orisirisi Ibi ta o re, b'a d'orun lo ja ju o Ibo lodo temi tire? Ore je ka roo Oba je ko san wa o, ka b'Olorun nile Opin irin ajo temi tire ninu aye Oba je ko san wa o, ka jagunmolu Jesu ti wa s'aye lati ku fun emi ati iwo, ore ma se ko ife Jesu yi o Nitori o san fun eniyan lati ma wa'ye rara, ju pe k'o pada s'orun apaadi lo Ore mi mo n be o, iku Jesu Kristi, mase je ko ja s'asan Oniwakuwa ronu k'o lo ja'wo Alagbere, oniwokuwo k'e ya so se Ole, janduku, e ku ireti ojo idajo K'aborisa ko pa un ti o soro ti k'o sin l'Ohun E ye bo satani lowo k'e tun f'enu ko Jesu S'eke, s'ajo ko s'eni t'o gb'alubosa, e gbo? To maa fi ka 'la o, iyen d'eewo Opin irin ajo temi, tire ninu aye Oba je ko san wa o, ka jagunmolu Aye o ni 'boji, orun ni 'boji aye Eni da 'mi siwaju lo n te 'le tutu Eni lo s'ajo to mi a de ti o ti ferese Iyen gbe 'se ile re f'onisona ko w'eyin wo rara K'o to dele, iji ka'ja, ojo wole p'eru Iboji a da ninu ile to ti d'aatan Eni ye ko wole mu'mi sinmi a tun ko sise Opin irin ajo, isinmi lo ye k'o je Ti e ba n gbo Bi e ba n gbo t'omode n ge 'gi ni 'gbo Agba lo le mo 'bi to mi a wo si B'omode ba rin irin ajo loju agba O le ma ba agba mo ni'le to ba de o Irin ajo eda laye, Olorun lo mo Opin irin ajo k'a fi s'adura Opin irin ajo temi tire ninu aye Oba je ko san wa o k'a jagunmolu Bi e ba n gbo t'omode n ge 'gi ni 'gbo Agba lo le mo 'bi to mi a wo si B'omode ba rin irin ajo loju agba O le ma ba agba mo ni'le to ba de o Irin ajo eda laye, Olorun lo mo Opin irin ajo k'a fi s'adura Opin irin ajo temi, tire ninu aye Oba je ko san wa o k'a jagunmolu
Writer(s): Bioku Holdings Llc Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out