歌词
Ori mi, ko ni buru o
Ori mi, ko ni buru o
Ori mi, ko ni buru o, yee
Ori mi, ko ni buru o
Letter t'Oluwa ba ko, ko seni to le pada
Ori mi, ko ni buru o
Ori mi, ko ni buru o
Ori mi, ko ni buru o
Ori mi, ko ni buru o
Ori mi, ko ni buru o
Letter t'Oluwa ba ko, ko seni to le pada
Ori mi, ko ni buru o
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Ire kaluku o, lowo Eleda lo wa
Oluwa ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Ire kaluku o, lowo Eleda lo wa
Oluwa ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Ire kaluku o, lowo Eleda lo wa
Oluwa, ko ma gbagbe mi
Written by: Ebenezer Obey


