album cover
Assignment
31,652
Music
Assignment 由 YBNL NATION 於 2017年9月13日發行,收錄於專輯《Assignment - Single》中
album cover
發行日期2017年9月13日
標籤YBNL NATION
旋律
原聲音質
Valence
節奏感
輕快
BPM123

音樂影片

音樂影片

積分

演出藝人
DJ Consequence
DJ Consequence
演出者
Olamide
Olamide
演出者
詞曲
DJ Consequence
DJ Consequence
詞曲創作

歌詞

[Intro]
Say Baddo
Wherever you see Young John, say Babo
Ah yo yo yo (Ah yo yo yo)
Say Baddo (Say Baddo)
Wherever you see Consequence, say Babo (Say baba o)
[Chorus]
Ti ko ba nidii obinrin o ki n jẹ Kumolu
Wọn lawa gbe bagi bi alajọ shomolu
Ti n ba gbowo nisin wọn a ni mo ṣe yahoo
Ti n ba wọ private jet, wọn a tun ni mo gawu
Wọn n wadii ẹ, assignment
Wọn n wadii ẹ, assignment
Home work yin niyẹn, assignment
Wọn n wadii ẹ, assignment
[Verse 1]
Slay queen ma pa mi now, baby take palmi now
Or you like Ribena, wo na you sabi now
Tinted dokodoko, fitted borokodo, yaro dokodoko
Na person farm, oko oloko
Na Boku foundation, fowo ṣe charity
Ta lo n jẹ Charity? Ẹ jọ ẹ ba wa wa Charity
Slay queen yii ti para, na money be moral
Jessica alora, ibadi nijo wa
[Bridge]
Ṣe Shomolu wa? Yes ke
O loyun o pọnmọ, yes ke
Epetedo nkọ? Yes ke, awọn t'Ambode, yes ke
Mushin Olosha da? Yes ke, wọn tinba sibẹ, yes ke
Ẹ ma ṣe were n'Bourdillon, ibẹ lọga wa
Update!
[Chorus]
Ti ko ba nidii obinrin o ki n jẹ Kumolu
Wọn lawa gbe bagi bi alajọ shomolu
Ti n ba gbowo nisin wọn a ni mo ṣe yahoo
Ti n ba wọ private jet, wọn a tun ni mo gawu
Wọn n wadii ẹ, assignment
Wọn n wadii ẹ, assignment
Home work yin niyẹn, assignment
Wọn n wadii ẹ, assignment
[Verse 2]
Like Paso, I wonder, please I'm not your brother
Mummy ẹ not my mother, ma ṣe were pass my border
My money, my cheda, ohun tun da, ẹ da pada
Na baba be father, who tell you that pọnmọ na lethal
Big like kushi kushi, wẹru Gucci Gucci
Fela Kuti Kuti, iṣẹ yẹn ro Sushi Sushi
Mr Preacher preacher, o fẹ mọ nnkan to pa'ya teacher
Who can fisher fisher, k'ọn fi were sinu shisha
[Bridge]
Ṣe Shomolu wa? Yes ke
O loyun o pọnmọ, yes ke
Epetedo nkọ? Yes ke, awọn t'Ambode, yes ke
Mushin Olosha da? Yes ke, wọn tinba sibẹ, yes ke
Ẹ ma ṣe were n'Bourdillon, ibẹ lọga wa
Update!
[Chorus]
Ti ko ba nidii obinrin o ki n jẹ Kumolu
Wọn lawa gbe bagi bi alajọ shomolu
Ti n ba gbowo nisin wọn a ni mo ṣe yahoo
Ti n ba wọ private jet, wọn a tun ni mo gawu
Wọn n wadii ẹ, assignment
Wọn n wadii ẹ, assignment
Home work yin niyẹn, assignment
Wọn n wadii ẹ, assignment
Written by: Dj Consequence
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...