積分
演出藝人
Gbenga Akinfenwa
演出者
詞曲
Gbenga Akinfenwa
詞曲創作
歌詞
[Chorus]
Kabiyesi rẹ
Kabiyesi rẹ
Ẹyin ṣoṣo lọba
Ẹ le wi, ẹ le ṣe
Kabiyesi rẹ
Kabiyesi rẹ
Mo wolẹ fun Kabiyesi rẹ
Ka bi ọ o si o
Kabiyesi rẹ
Kabiyesi rẹ
Ẹyin ṣoṣo lọba
Ẹ le wi, ẹ le ṣe
Kabiyesi rẹ
Kabiyesi rẹ
Mo wolẹ fun Kabiyesi rẹ
Oba toga toga tao le ropin rẹ
Mo wolẹ fun kabiyesi rẹ
Come on, come on, lift up your heads oh ye gates
[Verse 1]
Ẹ gbe ori yin soke
Ẹyin ilẹkun ayeraye
Ẹ gbe ori yin soke
Kọba ogo wọle wa
Kina tan yi itẹ rẹ ka
O sọrọ o dun bi ara
Ta lo le, ta lo le ba ọ ja o?
Alagbara giga laye lọrun
Laye lọrun e ma ma si o
[Chorus]
Kabiyesi rẹ
Kabiyesi rẹ
Ẹyin ṣoṣo lọba
Ẹ le wi, ẹ le ṣe
Kabiyesi rẹ
Kabiyesi rẹ
Mo wolẹ fun Kabiyesi rẹ
[Refrain]
Mo wolẹ fun ọ
Olodumare
Mowolẹ fun kabiyesi rẹ
Kabiyesi, Kabiyesi rẹ
Kabiyesi rẹ
Ẹyin ṣoṣo lọba
Ẹ le wi, ẹ le ṣe
Kabiyesi rẹ
Kabiyesi rẹ
[Bridge]
Mo wolẹ fun Kabiyesi rẹ
Mo wolẹ fun Kabiyesi rẹ
Mo wolẹ fun Kabiyesi rẹ
Mo wolẹ fun Kabiyesi rẹ
Mo wolẹ fun Kabiyesi rẹ
Mo wolẹ fun Kabiyesi rẹ
[Chorus]
Kabiyesi rẹ
Kabiyesi rẹ
Ẹyin ṣoṣo, ẹyin ṣoṣo lọba
Ẹ le wi
Kabiyesi rẹ
Kabiyesi rẹ
Mo wolẹ fun Kabiyesi rẹ
Written by: Gbenga Akinfenwa

