積分

演出藝人
Beebu
Beebu
演出者
詞曲
Tiri Leather
Tiri Leather
詞曲創作
Habeeb Oluwasegun Amoo
Habeeb Oluwasegun Amoo
詞曲創作
製作與工程團隊
Ojikutu Opeyemi ‘ TQ beats’
製作人

歌詞

Wọn fẹ gb'orin lẹ'nu mi
Wọn fẹ kin sọ journey mi
Òun oju mi ń ri
Wọn fẹ kin sọ story mi
Ṣé b'Ọlọhun lo ń sogo
Ṣé b'Ọlọhun lo ń sọla o
O le ma ni leni
Àlàyé mi ko ni l'ọla o
Wọn fẹ gb'orin lẹ'nu mi
Wọn fẹ kin sọ journey mi
Òun oju mi ń ri
Wọn fẹ kin sọ story mi
Ṣé b'Ọlọhun lo ń sogo
Ṣé b'Ọlọhun lo ń sọla o
O le ma ni leni
Àlàyé mi ko ni l'ọla o
Ilahi alaranse
Na only you me I go dey praise
Ọba tó jẹ wipe
Inside this struggle oun wo mi o
Mo dúpẹ Ọlọ́hun mi
Forever grateful sa l'èmi
Ojú Ògún sa láyé
Fún ẹni to wa ṣe rere
Everyday by day k'emi tẹ'wọ' gb'ọpẹ
Ọmọ ọlọpe tèmi kin ma sọpe
Make I Dey go high
Make I Dey fly high
Wọn fẹ gb'orin lẹ'nu mi
Wọn fẹ kin sọ journey mi
Oun ojú mi ń ri
Wọn fẹ kin sọ story mi
Ṣé b'Ọlọhun lo ń sogo
Ṣé b'Ọlọhun lo ń sọla o
O le ma ni leni
Àlàyé mi ko ni l'ọla o
Wọn fẹ gb'orin lẹ'nu mi
Wọn fẹ kin sọ journey mi
Oun ojú mi ń ri
Wọn fẹ kin sọ story mi
Ṣé b'Ọlọhun lo ń sogo
Ṣé b'Ọlọhun lo ń sọla o
O le ma ni leni
Àlàyé mi ko ni l'ọla o
If them know my story Kini wọn a se si?(Kini wọn a ṣe sí)
Baba to pe glory lo mọ ń ta se si
Ẹ'dá kan un sáré asan
Lala koko lórí asán
If you bless me father kini won a se si?(Baba kini wọn a se si o)
Everyday by day ke mi tẹ'wọ' gb'ọpẹ
Ọmọ ọlọpe tèmi kin ma gb'ọpẹ
Make I Dey go high
Make I Dey fly high
Wọn fẹ gbo'rin lẹ'nu mi
Wọn fẹ kin sọ journey mi
Òun ojú mi ń ri
Wọn fẹ kin sọ story mi
Ṣé b'Ọlọhun lo n sogo
Ṣé b'Ọlọhun lo n sọla o
O le ma ni leni
Àlàyé mi ko ni l'ọla a o
Wọn fẹ gb'orin lẹ'nu mi
Wọn fẹ kin sọ journey mi
Òun ojú mi ń ri
Wọn fẹ kin sọ story mi
Ṣé b'Ọlọhun lo ń sogo(Àlàmú Tiri mi re ó)
Ṣé b'Ọlọhun lo ń sọla o(OSP tí wọn ń so o)
O le ma ni leni(ahnn pelu Beebu)
Àlàyé mi ko ni l'ọla o
(Ah yà yà yà ah yà yà yà)
Èmi ni Beebu
(Ah yà yà yà ah yà yà yà ah yà yà ah yà yà can't lie eh ah yà yà yà ah yà yà yà)
OSP tí wọn ń sọ o
Written by: Alamu Tirimisiyu Leather, Habeeb Oluwasegun Amoo
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...