歌詞

Oluwaloṣeyi (I love you) (Yo D') This year na my year I can be the man of the year Mo ń gbe'le, cash out Wọn dẹ ni, "ko ni'ṣẹ" Lailah, mo n kira f'Ojiṣẹ Baby, jijo mi oh, ma ko sẹ Orente, no fit fight karate Oṣùbá rẹ re, ko s'oun t'Oluwa o le ṣé Ọmọdé ile, joromi a joro, ayy, ayy Money, money oh, every day Dantata, Dangote T'oju ba yẹ'ju, k'ohun ma ṣe yẹ I can be the man of the year You can be the man of the year too T'oju ba yẹ'ju, k'ohun ma ṣe yẹ I can be the man of the year You can be the man of the year too Ayy-ayy, ayy, verse two If you dance I go dance too Olomi, mo n calcu' Má lọ ro pe o ja ju Àá ni kagbako t'ẹbi t'ara Ire gbogbo nile awa Baby, gb'ẹsẹ, dey cat walk Orin, bami da ìmọ'ràn, uhn-uhn-uhn Orente, no fit fight karate Oṣùbá rẹ re, ko s'oun t'Oluwa o le ṣé Ọmọdé ile, joromi a joro, ayy, ayy Money, money oh, every day Dantata, Dangote T'oju ba yẹ'ju, k'ohun ma ṣe yẹ I can be the man of the year You can be the man of the year too T'oju ba yẹ'ju, k'ohun ma ṣe yẹ I can be the man of the year You can be the man of the year too T'oju ba yẹ'ju, k'ohun ma ṣé yẹ I can be the man of the year You can be the man of the year too (Yo Dibs)
Writer(s): Afolabi Oluwaloseyi, Olawale Adibe Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out