歌詞
[Intro]
Darrykay on this one, you know
Its Jeyfred the beat wizard
Omoola ah ah ahh
[Verse 1]
So many fasting and prayers
So many silent prayers
But alubarika lo ju
After sapa dajupa lo ku
Mo ma ki Halleluyah
Me and poverty gats to pinya
Ahh, pinya ah
Me and poverty gats to pinya ah
Many days mama pray for me
Dem dey hate iyẹn ko kan mi
Wọn n binu wọn tun sọrọ mi
Do-re-mi-fa-so, do-re-mi
Many days mama pray for me
Dem dey hate iyẹn ko kan mi
Wọn n binu wọn tun sọrọ mi
Do-re-mi-fa-so, do-re-mi
[Chorus]
Edumare jọ, jọ dakun gbẹbẹ mi
As I dey steady on my grind o
K'ọta ma yọ mi o
Edumare jọ, jọ dakun gbẹbẹ mi
As I dey steady on my grind o
K'ọta ma yọ mi o
[Verse 2]
More blessing pupọ lọdọ mi
Awọn ọrẹ mi sọmu dọta mi
Sago ẹni i ma do pa mi
Edumare jọ, jọ dakun gbẹbẹ mi o
Ti ba yẹ k'ọn maa sọrọ mi
Ọrọ t'ọn sọ iyẹn ko kan mi
[Verse 3]
Ọmọ iya mi ṣẹ ẹ
Ti ba ṣẹ ẹ ko pẹlẹ
Ta dẹ n sare mọto ta n sare ko daa
Ka ma rọlu ẹlẹyin pẹlu kẹkẹ
So many sleepless night kini ka sọ
Many heated night ti mo baṣọ
Ti ba yẹ k'ọn maa sọrọ mi
Ọrọ t'ọn sọ iyẹn ko kan mi
[Chorus]
Edumare jọ, jọ dakun gbẹbẹ mi
As I dey steady on my grind o
K'ọta ma yọ mi o
Edumare jọ, jọ dakun gbẹbẹ mi
As I dey steady on my grind o
K'ọta ma yọ mi o
[Outro]
More blessing pupọ lọdọ mi
Awọn ọrẹ mi sọmu dọta mi
Sago ẹni i ma do pa mi
Edumare jọ, jọ dakun gbẹbẹ mi
Ti ba yẹ k'ọn maa sọrọ mi
Ọrọ t'ọn sọ iyẹn ko kan mi o
Written by: Okedele Oluwamilare Abefe