歌詞
[Verse 1]
Ọmọ Ògúnléyẹ
Èmi àti ẹ lawọ balùwẹ̀
Ọmọ Ògúnléyẹ
Èmi àti ẹ lawọ balùwẹ̀
[Chorus]
Ìlẹ̀kẹ̀ já o
Ìlẹ̀kẹ̀ já ó já tòun tòwú
Ìlẹ̀kẹ̀ já o
Ìlẹ̀kẹ̀ já o ja tòun tòwú
Má fi mí ṣọ́ wọn
Ma fi mí ṣọ́ àwọn ọ̀rẹ́ ẹ ó léwu
Má fi mí ṣọ́ wọn
Má fi mí ṣọ́ àwọn ọ̀rẹ́ ẹ ó léwu
A rán ni níṣẹ
A rán ni níṣẹ́ dé tòrutòru
A rán ni níṣẹ
A rán ni níṣẹ́ dé tòrutòru
[Verse 2]
Mo di márosẹ̀ mo ti ṣá lọ mọ'bẹ̀
Èmi márosẹ̀ èmi ṣá lawo'bẹ̀
Kútúpà ẹṣin gàǹgà
Kútúpà ẹṣin gàǹgà
Mo di márosẹ̀ mo ti sá lọ mọ'bẹ̀
Èmi márosẹ̀ èmi ṣá lawo'bẹ̀
Ilé wa ládùn
Ẹ̀lẹ̀ mi jẹ́ ká relé
Ilé wá ládùn
Ẹ̀lẹ̀ mi jẹ́ ká relé
Ẹ̀lẹ̀ mi
[Verse 3]
Da bí ọgbọ́n ko pawó
Pawó ẹ tan ko jayé
Da bí ọgbọ́n ko pawó
Pawó ẹ tan ko jayé
[Verse 4]
Ọmọ Ògúnléyẹ
Èmi àti ẹ lawọ balùwẹ̀
Ọmọ Ògúnléyẹ
Èmi àti ẹ lawọ balùwẹ̀
Mo ti lọ mọ’bẹ̀
Mo ti ṣawo ibẹ̀
Ọmọ Ògúnléyẹ
Èmi àti ẹ lawọ balùwẹ̀
Mo di márosẹ̀ mo ti ṣá lọ mọ'bẹ̀
Èmi márosẹ̀ èmi ṣá l'awo ibẹ̀
[Chorus]
Ìlẹ̀kẹ̀ já o
Ìlẹ̀kẹ̀ já ó já tòun tòwú
Ìlẹ̀kẹ̀ já o
Ìlẹ̀kẹ̀ já ó já tòun tòwú
Má fi mí ṣọ́ wọn
Ma fi mí ṣọ́ àwọn ọ̀rẹ́ ẹ ó léwu
Má fi mí ṣọ́ wọn
Má fi mí ṣọ́ àwọn ọ̀rẹ́ ẹ ó léwu
A rán ni níṣẹ
A rán ni níṣẹ́ dé tòrutòru
A rán ni níṣẹ
A rán ni níṣẹ́ dé tòrutòru
[Outro]
(Bizzle on the mix)
Written by: Alexander Abolore Adegbola Akande


