音樂影片
音樂影片
積分
演出藝人
JayMikee
演出者
Gaise Baba
演出者
Joshua Isreal
演出者
Daddy Verse
演出者
詞曲
Joshua Isreal
詞曲創作
Daddy Verse
詞曲創作
Joshua Mike-Bamiloye
詞曲創作
Akinade Ibuoye
詞曲創作
製作與工程團隊
JayMikee
製作人
歌詞
Agbára
Tó ju agbára lo
Agbára
Verse 1 - Daddy Verse
Ehhh
Omo, we wrestle, sómo
Ko ya mo'bi to ma to si o
Life is a battle, sómo
Ogun laye ore, powers clash
Iseju kan pere, wo yawa gas
Omo, ole lo ma fori e fágbon
I go meet person wey get power pass
Mo sa wonu Jesu, mo ti gbaradi
Mo ti gba agbára to gbagbára mi
Awon ogun orun ready pelu ida lowo
Anytime to ba díjakadi
Agbára ti Mose fi pókun niya
Sona kale fun woli Elijah
Ti m nba activate
Ko nse sere sere o
To ba ti ri mi, koya
Wo, ma lo speculate
Esu daddy yin gan
Tó ba gbóruko Jesu, a sa
Sómo
Agbára
Tó ju agbára lo
Agbára
Ina n jo ogun esu fe lele
Agbára
Tó ju agbára lo
Agbára
Verse 2- Joshua Israel
Eni ti oju re nko monamona
Iri si Oluwa nba ni leru jojo
Owo Oluwa nfa igi kedari ya o
Oruko Oluwa Ile ise agbára
Esu, wa bigba, sogi gun
Sada nu, Jada nu
Ehhhh
Mo ni o re lule, Ja lule
Ku danu, sa lule
Ki o da san
Esu, wa bigba, sogi gun
Sada nu, Jada nu
Ehhhh
Mo ni ore lule, Ja lule
Ku danu, sa lule
Ki o d'fo oooh
Agbára
Tó ju agbára lo
Agbára
Ina n jo ogun esu fe lele
Agbára
Tó ju agbára lo
Agbára
Verse 3 - Gaise Baba
I get rod for hand
Dem get rod for hand, too
I drop rod for ground
Dem drop theirs, too
Opa mi déjo
Opa awon naa déjo
Sugbon ejo won dóunje féjo mi
Taani iwo oke nla
Iwo yoo di petele
Niwaju Zerubbabel
Taani iwo oke nla o
Iwo yoo di petele
Niwaju Zerubbabel
They can't step to this
Principalities can't step to this
Rulers of the darkness
Can't step to this
Even spiritual wickedness
They can't step to this, yeah
Agbára
Tó ju agbára lo
Agbára
Ina n jo ogun esu fe lele
Agbára
Tó ju agbára lo
Agbára
Bridge - JayMikee
Chants
They can't step to this
Principalities can't step to this
Rulers of the darkness
Can't step to this
Even spiritual wickedness
They can't step to this, yeah
They can't step to this
Principalities can't step to this
Rulers of the darkness
Can't step to this
Agbára
Tó ju agbára lo
Agbára
Ina n jo ogun esu fe lele
Agbára
Tó ju agbára lo
Agbára
Ina n jo ogun esu fe lele
Ina n jo ogun esu fe lele
Ina n jo ogun esu fe lele
Agbára
Tó ju agbára lo
Agbára
Ina n jo ogun esu fe lele
Agbára
Tó ju agbára lo
Agbára
Written by: Akinade Ibuoye, Daddy Verse, Joshua Isreal, Joshua Mike-Bamiloye


