album cover
Tinuke
50,802
Dance
Tinuke 由 © King Soundboi Music 於 2025年8月23日發行,收錄於專輯《PREMIUM LAMBA》中
album cover
發行日期2025年8月23日
標籤© King Soundboi Music
旋律
原聲音質
Valence
節奏感
輕快
BPM111

音樂影片

音樂影片

積分

演出藝人
Folarin Usman Babatunde
Folarin Usman Babatunde
演唱
詞曲
Folarin Usman Babatunde
Folarin Usman Babatunde
詞曲創作
製作與工程團隊
Soundboi Beatz (Let Him Nak)
Soundboi Beatz (Let Him Nak)
製作人

歌詞

[Intro]
Ah zoom zoom
[Verse 1]
Oluwa lo n ṣọ wa awa o need aja
But a le gba doggy
Ti Fọlarin ba mu beat aya beat a ja
Lori amapaino
Tori idiganlebe wọn fẹ impeach awa
Ah akoi yansh
Furọ ti o ba ti ki i ṣe furọ GLA
Ko le freak awa, ko dẹ le fit awa
Tinukẹ n do piti, o n gbe maalu mi tiwotiwo lodindi (Hey)
Iru iwa yẹn nibo lo ti ri? Ta lo tun fẹ fi jọ, obi to bi ni (Ah)
Wọn lo n do yati, pe o n do ṣege
Bo ṣe n jo disco lo n jo reggae
Fun wa n number jẹ ka patronise ẹ
Sọrọ owo ka mọ price ẹ
Jẹ ka ṣe lọwọ dere iwọ naa mọ mi o kere
Mi o kere
Mo mọ pe mi o holy but ọmọ woli ni mi beere lọwọ Dele
[Chorus]
Tẹ ba ti ri Tinukẹ
Tinukẹ
Ẹ sọ fun pe mo dupẹ
Mo dupẹ
Gbogbo kissing gbogbo
Hugging
Gbogbo missionary gbogbo
Doggy
Tẹ ba ti ri Tinukẹ
Tinukẹ
Ẹ sọfun pe mo dupẹ
Mo dupẹ
Gbogbo kissing gbogbo
Hugging
Gbogbo missionary gbogbo
Doggy
[Verse 2]
Ọmọ igba wo lo ja na?
Gbogbo scope mi lo ti ka tan
Mo ti fọ tan
Ọmọge wa na I go chop before I chop you, ṣo le dana?
Baby ṣo le dana?
O mọ pe mo ko ẹ jẹ bi ti Sushi (Hey)
Gbọn ẹ mu bi ti skushi (Ah)
Ọmọ ẹlẹ to dun bi elle
No rushing ṣe mi pẹlẹ
Fun mi l'amapiano gbẹmigbẹmi (Aibo)
Ti n ba ri furọ mi o ki n dẹyin
Tinukẹ ṣe mi loore mo fẹ dupẹ
Gba mi laago to ba ti ri Tinukẹ
[Chorus]
Tinu (Tinukẹ)
Ẹ sọ fun pe mo dupẹ
Mo dupẹ
Gbogbo kissing gbogbo
Hugging
Gbogbo missionary gbogbo
Doggy
Tẹ ba ti ri Tinukẹ
Tinukẹ
Ẹ sọfun pe mo dupẹ
Mo dupẹ
Gbogbo kissing gbogbo
Hugging
Gbogbo missionary gbogbo
Doggy
[Outro]
Fọlarin olorin!
Written by: Folarin Usman Babatunde
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...