Lyrics

Kewu ní má fí wọlé Kewu ní má fí wọlé ooh Ilé ológo, ilé aláyọ' Kewu ní má fí wọlé Achalafuli jarafa karimu Seribumi, serifa, seruku Serimoka, serifa, kalisada deli ihh Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh (Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́) Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh (Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́) Ma da faliu, ma da selifa Senseburi molaika, ibura kanka buriji madansimo seliu Kò oloṣo tó dí slay mama, iṣẹ ló mà ṣe Alert mí má dún, ojú yìn ló mà ṣé Ilé o, gbọọrọ Olùwà, lórí rẹ má ṣe'un ire Jẹ kó mà ṣẹgàn, kó má ṣábosì Ọmọ ológo, mà gbérà Elohi' o, ìwọ Àdàbà Elohi' o, ìwọ Àdàbà ah Àdàbà tó wà nínù ọgbà, Àdàbà Mímọ' ni Àdàbà yí o, wọlé Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh (Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́) Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh (Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́) B'ómi ṣé wọnú àgbọn mí, kò ṣeni tó yẹ Ọlọrun o, motelimo, sarifa tali Mà jẹ k'àyé bù mí pé camera mí ó dà Mà jẹ k'àyé fí mí ṣẹ̀sín pé ìwà mí ó dà Ọlọrun Mósè, M'Orimolade Tumolaṣe Bàbá dàmí lóhùn aiye' mí ré, bà mí túnṣe Elohi' o, ìwọ Àdàbà Elohi' o, ìwọ Àdàbà ah Àdàbà tó wà nínù ọgbà, Àdàbà Mímọ' ni Àdàbà yí o, wọlé Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh (Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́) Mẹta, mẹta l'àtẹ́wọ́ ìyè yí oh (Atẹ́wọ́, eh-eh, yeah, atẹ́wọ́) Ọmọ Cherubim, Seraphim You gats to be prayerful Torí pé, ibarasa lamalifu Agbara luselifa Seribumi, serifumi, elédè kewu Ijiria falibu, saliabana kalifi Mada selihu lona mefa Mò pàṣẹ fowó inú afẹ'fẹ' Kò má padà sínú afẹ'fẹ' mọ À tí parí ẹ o
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out