Lyrics

Mo de o baba Mo wa sope Ore nla Baba ti gba awon Omo e O tunminu Ebami dupe f'oluwa to ranmilowo Baba gba mi lowo isubu at'omije Kini on'fi fun oluwa fun Ore re Ope mi pe'lesin mi o tunmininu Mo ti da majemu o e Un o San majemu mi o a Fun baba olore ofe To se'leri to muse o a Mo de o baba Mo wa sope Ore nla Baba ti gba awon Omo e O tunminu Ebami dupe f'oluwa to ranmilowo Baba gba mi lowo isubu at'omije Kini on'fi fun oluwa fun Ore re Ope mi pe'lesin mi o tunmininu Mo ti da majemu o e Un o San majemu mi o a Fun baba olore ofe To se'leri to muse o a Ore Ofe lo da mi si Mo mo ye na Mo d'olola loju ota mi o Emi ajo Iku fo lo arun segbe o - eyi tope Baba Wole eti odo mi o ranmilowo Eba mi Jo eyin ara mi ile aye Kope yi o ko wa ka la n toro Mo ti da majemu o e Un o San majemu mi o a Fun baba olore ofe To se'leri to muse o a
Writer(s): King Sunny Ade Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out