Lyrics

Koni ku o Rọmọla Ofeṣe Koni ku o Sunny mi o ni ku o Rọmọla Ofeṣe Koni ku o Tori gunugun kii ku s'ewe O ṣe'wọ o Ẹnikan ki ba alágẹmọ labẹ ewe Bẹẹni, a kì ma rọ gidigba la lẹ odo Koni ku sẹ Rọmọla Ofeṣe Koni ku o Adìyẹ yo, adìyẹ pogun Wan l'adiye ro p'ọmọ rẹ Adìyẹ rọgbọn, adìyẹ pọgbọn Wan l'adiye ro p'ọmọ rẹ Wan binu gb'adiyẹ ta Wan f'owo ra'wo Awo y'ẹyin mẹfa O fi pa kan ṣoṣo Ọkan ṣoṣo girogiro Ọkan ṣoṣo l'ẹrin n ṣe gbo Ọkan ṣoṣo r'ẹfan ni sọdan Ọkan ṣoṣo l'ajanaku nimi gbo kiji-kiji-kiji Awa ti b'egun ja o Aṣẹgun re'gungun Ati b'ọrìṣà já o Awa d'oriṣa kunlẹ bọ Awọn agbejọ ra lo f'ọlọrun ọba Bambaa ni baba n da Ẹni t'ọlọrun ba ti dá Ko ṣe f'arawe Ko ṣe f'arawe Bamba ni n baba da wa o Ko ṣe f'arawe Ẹni tí Ọlọrun ba ti dá n nkọ Ko ṣe f'arawe Gbamugbamu jigijigi Ko ṣe f'arawe
Writer(s): Sunny Ade Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out