Lyrics

Jesu! Imole! Ategun ati Afara S'ibi Imole Jesu! Eni t'O wa Ife Baba S'eni to fe d'omo Jesu! Imole! Ategun ati Afara S'ibi Imole Jesu! Eni t'O wa Ife Baba S'eni to fe d'omo Jesu! Imole! Ategun ati Afara S'ibi Imole Jesu! Eni t'O wa Ife Baba S'eni to fe d'omo Imole, lati 'nu Imole O wa lati da wa pada S'ona Imole Ookun to gb' aye Ko je k' 'on mo Imole Won dite mo mo o, Ife Baba Olorun ninu eniyan Eniyan ninu Olorun Ilekun awon aguntan S'inu ile aanu Ipase eni ti mo gba igbala ati ilaja s'odo Baba B' aye ti n fi fun ni ko Imole s'ookun aye mi Olu se 'wosan emi mi Jesu! Imole! Ategun ati Afara S'ibi Imole Jesu! Eni t'O wa Ife Baba S'eni to fe d'omo Jesu! Imole! Ategun ati afara S'ibi Imole Jesu! Eni t'O wa Ife Baba S'eni to fe d'omo Eni wa Imole Won n ri Imole Won o mo Imole Won n dite imole Irora yen po gan Eje at' omi san gan Sibe O s' agbawi fun wa Wipe Baba dariji won Won o mo n t' 'on se S' a ti mo 'n a n se Baba, dariji wa o, nitori Imole Ninu irora Re, o tun fi iyonu mu ole *** O ni "Iya wo omo re, Omo wo iya Re" O kigbe lohun rara: "Olorun mi, eese t' O ko mi i le..." "Eese to ju mi le, eese t' O yin mi nu?" Oungbe po gan, oti kikan laye fun Un Awon to wa Imole o, won n fi 'ya je Imole O ba pari, O pari! Imole f' emi E s'owo Baba O pari! Nitori Imole Aso ikele ya o Nitori Imole A le pe Baba ni Baba Nitori Imole Isa oku d'ofo Eni ba fe le wa d'omo Jesu! Oga Ogo! Olori Ogun Orun! Omo Alade Alaafia! Alase Orun! Aye Baba! Baba laaye o! Baba laye! Aye mi, Tire ni Tan Imole nipase mi Ogo mi k'o f'ogo fun O Ola mi k'o bu ola fun O! Jesu! Iwo ni 'Mole! Iwo ni Afara! S'ibi ategun Imole Jesu! Iwo ni Eni naa t'O wa Mo juba Re, Eni to so mi d'omo
Writer(s): Sola Allyson Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out