Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
Tunji Oyelana
Tunji Oyelana
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Tunji Oyelana
Tunji Oyelana
Lyrics

Lyrics

Eni n binu Koma ma binu Onibaje ye sebaje Alaru ton Je buredi Se awo orie lonje tikomo Iwo aseni Ye seni mo Oni Jamba ye seka mo Alaru ton Je buredi Se awo orie lonje ti komo Aronipin ranti iwaju Aiye le yipada bo dola Alaru ton Je buredi Se awo orie lonje ti komo Eni fe sare ko ma sare Ma di eni ton satire lese mu Alaru ton Je buredi Se awo orie lonje ti komo
Writer(s): Tunji Oyelana Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out