Music Video

Awodi
Watch {trackName} music video by {artistName}

Credits

PERFORMING ARTISTS
Asake
Asake
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Olamide Adedeji
Olamide Adedeji
Songwriter
Ahmed Olalade
Ahmed Olalade
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Magicsticks
Magicsticks
Producer

Lyrics

(Ọlọlade mi, Àṣàkẹ) (Tune in to the king of sounds and blues) Àwòdì fo lókè, o fẹ d'Olùwà Ẹribi, ẹribi, I wonder oo Wonder shall never end (wonder) like Pasuma, I wonder I wonder, Americana wonder oo Kíní reason? Kíní plan? Kíní scope? Why the beefing? Catfish lórí títí Jẹ bí chicken, ṣọbọleyọke jú killing (killing) Iwájú gán o easy, ẹhìn o ṣé lọ, ọmọ ìyá mí, ṣo tí rísìnyí (rísìnyí) My ship never sinking, mó kanaku, mó jiggy They wanna know what I'm thinking Many, many things, I no fit ṣàlàyé o 2022, mó gbé wọn trabayé o Olùwà ló gbé from the slum to the top Èmí kọ, àwọn kọ, wọn o lé t'Ọlọrun Ìṣù jọba lórí ìyàn Kémí má ní ìjọba òṣìkà Òjo l'ọkọ àgbàdo As e dey go, jásí, my nigga Aroma ńjo gẹ́, aroma ńle wọn Aroma ńdé bẹ, fabẹ yá o Mó ge wọn bí Babayaro Akabi Kaola, óyà, kabi lórí àwá o Àwòdì fo lókè, o fẹ d'Olùwà Ẹribi, ẹribi, I wonder oo Wonder shall never end (wonder) like Pasuma, I wonder ('der) I wonder, Americana wonder oo Kíní reason? Kíní plan? Kíní scope? Why the beefing? Catfish lórí títí Jẹ bí chicken, ṣọbọleyọke jú killing (killing) Iwájú gán o easy, ẹhìn o ṣé lọ, ọmọ ìyá mí, ṣo tí rísìnyí (rísìnyí) My ship never sinking, mó kanaku, mó jiggy They wanna know what I'm thinking They wanna know (aroma re o) They wanna know (aroma re o) Aroma ńjo gẹ, aroma ńle wọn Aroma ńde bẹ fàbẹ yá o Mó ge wọn bí Babayaro Akabi Kaola, ó yà, kabi lórí àwá o
Writer(s): Temitayo Kareem, Ololade Ahmed, Olamide Adedeji Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out