Lyrics

ELDee e-e-e-e-e LKT eh-eh And another one And another one Ọ'tá mí o ní ya f'ọkọ Akoyoyo ní o kàn lẹsẹ Agbe gẹdú ní o kàn lo run Ọmọ lanke ní o wo lẹ'yìn Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai È wá na, è wa na, e ba mi gbọ Ẹlẹ'dà mí ní òun tí sọ Kò sọ'nà t'ele gbé gbá wá Kò sára t'ele fẹ wá dá Àwa tí wo express As He don bless, no man can test Ko si'ṣòro, eyín lo ń stress A'tajẹ, a'toṣó, ẹ confess Wọn sa'rè wọn (wọn rí wá mù) Wọn kọrin wọn (wọn rí wá mú) Wọn tí wá lo (wọn rí wa sun) Wọn lu gẹmbẹ (a gbọ' kò dùn) Olúwa mí lo ń ṣìnà Ìkà tẹ ṣe lo ń dínà Ìrawọ́ wá e, lo ń tan'nà, lo ń tan'ná (lo ń tan'ná) Ọ'tá mí o ní ya f'ọkọ (ya f'ọkọ) Akoyoyo ní o kan lẹsẹ (kàn lẹsẹ) Agbe gẹdú ní o kàn lo run (kàn lọ run) Ọmọ lanke ní o wo lẹ'yìn (wo lẹ'yìn o) Àwa má rìn bai (rìn bai), rìn bai, rìn bai (rìn rege-rege) Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (atun lu raga-raga, raga-raga, raga-raga) Ẹ tẹti, ẹ tẹti yìn kẹ gbọ mí Bàbá God, òun lọ ń sọ mí Làti ibẹrẹ, òun lọ ń gbọ' mí Without Him, l am nobody Emí de recognise Òun lọ jẹ ka commercialize Tá le fí le má enterprise Ìlù to dùn àti ohùn to nice Wọn ṣá're wọn (wọn rí wá mú) Wọn kọrin wọn (wọn rí wá mú) Wọn tí wá lọ (wọn rí wá sun) Wọn lu gẹmbẹ (a gbọ ko dùn) Olúwa mí lọ ń ṣìnà Ìka tè ṣe lọ ń dínà Irawo wa, lọ ń tan'ná, lọ ń tan'na (lọ ń tan'ná) Ọ'tá mí o ni ya f'ọkọ (ya f'ọkọ) Akoyoyo ní o kàn lẹsẹ (kàn lẹsẹ) Agbe gedu ní o kàn lọrun (kàn lọ run) Ọmọ lanke ní o wo lẹ'yìn (wo lẹ'yìn o) Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai T'alajá wọn pa kúrú mo? Ta lopolo wọn dé rú bá oo? Àwọn báwo Ye! Lórí ọwọ wo? Àwọn kèké oguro, tí mo tí jẹun lọ Ye! Ẹ gbójú ń bẹ o Ẹ jáwọ́ ń bẹ o Bẹ̀bẹ̀ ṣí ń bẹ o Àyé ṣí ń lọ o Wọn ní ká m'ẹnì Olá la má mú È bá mí yọ o Ko fọwọ' ṣeré, f'ọmọ ṣeré, fẹ'Hennesy ṣòwò È sá rí o Ọ'tá mí o ni ya f'ọkọ (ya f'ọkọ) Akoyoyo ní o kàn lẹsẹ (kàn lẹsẹ) Agbe gedu ní o kàn lọ run (kàn lọ run) Ọmọ lanke ní o wo léyìn (wo lẹ'yìn o) Àwa má rìn bai (rìn bai), rìn bai, rìn bai (rìn rege-rege) Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (atun lu raga-raga, raga-raga, raga-raga) Ọ'tá mí o ní ya f'ọkọ (ya f'ọkọ) Akoyoyo ní o kàn lese (kàn lẹsẹ) Agbe gedu ní o kàn lọ run (kàn lọ run) Ọmọ lanke ní o wo lẹ'yìn (wo lẹ'yìn gan) Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (ko ríran mo) Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (rìn raga-raga ah-ah) Wọn sá're wọn (wọn rí wá mù) Wọn kọrin wọn (wọn rí wá mù) Wọn tí wá lọ (wọn rí wá sun) Wọn lu gẹmbẹ (a gbọ' kò dún) Olúwa mí lọ ń ṣìnà Ìka tẹ ṣe lọ ń dínà Ìrawọ́ wa, lo ń tan'nà, lo ń tan'nà (lọ ń tan'ná) Ọ'tá mí o ní ya f'ọkọ (ya f'ọkọ) Akoyoyo ní o kàn lese (kàn lẹsẹ) Agbe gedu ní o kàn l'orun (kàn lọ run) Ọmọ lanke ní o wo lẹ'yìn (wo lẹ'yìn o) Àwa má rìn bai (rìn bai), rìn bai, rìn bai (rìn rege-rege) Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (atun lu raga-raga, raga-raga, raga-raga) Ọ'tá mí o ní ya f'ọkọ (ya f'ọkọ) Akoyoyo ní o kàn lẹsẹ (kàn lẹsẹ) Agbe gedu ní o kàn lọ run (kàn lọ run) Ọmọ lanke ní o wo lẹ'yìn (wo lẹ'yìn gan) Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (ko ríran mo) Àwa má rìn bai, rìn bai, rìn bai (rìn raga-raga ah-ah)
Writer(s): Sikirullahi Dabiri, Tunde Olalekan Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out