Music Video
Music Video
Credits
PERFORMING ARTISTS
Sola Allyson
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Sola Allyson
Songwriter
Wilson Joel
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Wilson Joel
Producer
The SolaAllyson Limited
Producer
TML
Producer
Lyrics
[Chorus]
Gbe mi wọ lọtun, mo tẹwọ
Iri ko sẹ le mi o
Gbe mi wọ lọtun, mo tẹwọ
Iri ko sẹ le mi o
Imọlẹ ko tan lọtun sọna mi
Itura ko ba le mi lat'ọdọ Rẹ
Gbe mi wọ lọtun, mo tẹwọ
Iri ko sẹ le mi o
[Chorus]
Gbe mi wọ lọtun, mo tẹwọ
Iri ko sẹ le mi o
Gbe mi wọ lọtun, mo tẹwọ
Iri ko sẹ le mi o
Imọlẹ ko tan lọtun sọna mi
Itura ko ba le mi lat'ọdọ Rẹ
Gbe mi wọ lọtun, mo tẹwọ
Iri ko sẹ le mi o
[Verse 1]
To mi sọna lati rin Olutọna mi
Okunkun ko ka kuro tanmọlẹ ọtun
Ki n rin lọna naa t'O fẹ oye ko ye mi
Maa rin, maa mọ oye a ye mi ninu ifẹ Rẹ
[Verse 2]
Ẹni t'O ni ẹmi mi gbe mi wọ
Gbe mi wọ lọtun, mo tẹwọ
Iri ko sẹ le mi o
Gbe mi wọ lọtun, mo tẹwọ
Iri ko sẹ le mi o
Imọlẹ ko tan lọtun sọna mi
Itura ko ba le mi latọdọ Rẹ
Gbe mi wọ lọtun, mo tẹwọ
Iri ko sẹ le mi o
[Verse 3]
Igba ti idanwo ba de o
Oluwa ṣọ mi
Ọna maa ṣu nigba mii, nigba ti ọna mi ba ṣu, Oluwa o
Adaba tọ mi
Imọlẹ latọrun ko tan sọna mi, ko ma tan nigba gbogbo o
Ọna yẹn ko ma ṣe di
Agbara laye atọrun ọwọ Rẹ lo wa, ko sẹlomii lẹyin Rẹ
Iwọ nikan ni
Iwọ nikan naa n mo fẹ, Oluwa
Ṣa maa tọ mi lọ
Nigba ti o rẹ ọkan mi o
Iri sẹ le mi o
Written by: Sola Allyson, Wilson Joel