Lyrics

(No one is sleeker) Wọn ní kiń wá bàbá tó sabi K'owá w'orí mi, k'òtò saasi Kíń má ṣe ya'wó l'ọwọ Lati Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o Wọn ní kiń wá bàbá tó sabi o (ehn-ehn, ehn) K'owá w'orí mí, k'òtò saasi (uhn-uhn, uhn) Kiń má ṣe ya'wó l'ọwọ Lati Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o Uh, ọmọ ológo tó sabi Ọmọ gbéra tán, ò b'omi sí garri Ò wọ Yankee o, Atlanta per roof Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún Uh, ọmọ ológo tó sabi Ọmọ gbéra tán o, ò b'omi sí garri Ò wọ Yankee o, Atlanta per roof Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún Huh, kí lódé o jere o? Mo má j'àyé mí kọto fun fèrè o Uh, oṣe o, oṣe, oṣe o jere o Tińbá ṣíṣẹ́, kíń má ko'rè oko dé'lé o Uh, wọn gùn'yàn mí kéré o Mo fíìmù wọn fọn fèrè o Nínú àyé, mí o kéré o T'obà dé ìgbòrò, k'olo béèrè o Wọn ní kiń wá bàbá tó sabi o K'owá w'orí mi, k'òtò saasi Kiń má ṣe ya'wó l'ọwọ Lati Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o Wọn ní kiń wá bàbá tó sabi oh (ehn-ehn, ehn) K'owá w'orí mí, k'òtò saasi (uhn-uhn, uhn) Kíń má ṣe ya'wó l'ọwọ Lati Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o Uh, ọmọ ológo tó sabi Ọmọ gbéra tán o, ò b'omi sí garri Ò wọ Yankee o, Atlanta per roof Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún Huh, ọmọ ológo tó sabi Ọmọ gbéra tán o, ò b'omi sí garri Ò wọ Yankee o, Atlanta per roof Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún Huh, kí lódé o jere o? Mo má j'àyé mí kọto fun fèrè o Uh, oṣe o, oṣe, oṣe o jere o Tińbá ṣíṣẹ́, kiń má ko'rè oko dé'lé o Uh, wọn gùn'yàn mí kéré o Mo fíìmù wọn fọn fèrè o Nínú àyé, mí o kéré T'obà dé ìgbòrò, k'olo béèrè o I will exalt You, Lord For You have lifted me up Has not let my foes to rejoice over me (Timi Jay on the track)
Writer(s): Ayodele Ibukunoluwa, Promise Aloba Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out