Lyrics

Ojó tó tí pé Oná ti jìn Ó ti rò wa lorùn gan bí èko Eni à jùlo ò mò Ara ló jú opón Tán bán tàn é Jòwó kó o má tan raa rèe Irú Òkéré lóun ní a májá lérú Oun téo leesé lén rawólé pápin Àtokán Àtokàn irú won nínu Ilé Orin Erú olóko àwa nì won jé Mo sèbà fáwon ti De' Vil Selfpaid Records, OG Waliyi Mr Tosin, sájé' n wogbá Ofé ya photo Pe baba Jayden Bravolee tún ti sanwó mi Èyan Olómi tó 'n ta BTC Egbémidébè kín kí Israel Money Gbogbowá tii màn pé òhun ló ni Moní E tannán sáwon balógun Málo béé sí won Kóo máa lo gbì Àwon a pète pèrò Káa fowon wan lélè Tán tún yàká sí everybody Àwáá náàni táa múgboro dùn Kaniel Pèdè Ó mórí wa wú Tàsà tèdè kalè sódò wa Nitori Ojó tó tí pé Oná ti jìn Ó ti rò wa lorùn gan bí èko Eni à jùlo ò mò Ara ló jú opón Tán bán tàn é Jòwó kó o má tan raa rèe Irú Òkéré lóun ní a májá lérú Oun téo leesé lén rawólé pápin Àtokán Àtokàn irú won nínu Ilé Orin Erú olóko àwa nì won jé Ojó tó tí pé Oná ti jìn Ó ti rò wa lorùn gan bí èko Eni à jùlo ò mò Ara ló jú opón Tán bán tàn é Jòwó kó o má tan raa rèe Irú Òkéré lóun ní a májá lérú Oun téo leesé lén rawólé pápin Àtokán Àtokàn irú won nínu Ilé Orin Erú olóko àwa nì won jé Ojó tó tí pé Oná ti jìn Ó ti rò wa lorùn gan bí èko Eni à jùlo ò mò Ara ló jú opón Tán bán tàn é Jòwó kó o má tan raa rèe Irú Òkéré lóun ní a májá lérú Oun téo leesé lén rawólé pápin Àtokán Àtokàn irú won nínu Ilé Orin Erú olóko àwa nì won jé (Ona ti Jin) (Bi eko) (Ara loju opon) (Mátan raa re) (Rawole papin) (Ninu ile orin) (Eru oloko awa ni won je) Ojó tó tí pé Oná ti jìn Ó ti rò wa lorùn gan bí èko Eni à jùlo ò mò Ara ló jú opón Tán bán tàn é Jòwó kó o má tan raa rèe Irú Òkéré lóun ní a májá lérú Oun téo leesé lén rawólé pápin Àtokán Àtokàn irú won nínu Ilé Orin Erú olóko àwa nì won jé
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out