Lyrics

Interlude Mashaallah Eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o Maf'ikankan, dunmi nibe oba nla Eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o Maf'ikankan, dunmi nibe oba nla Tor'odi o loun tole fi toro, sungbon o lokan tole fi beere O sha nd'odi loun lori oore, kod'igba tinba so soke kaye o gbo o Koto dami loun oba nla ilahi Eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o Maf'ikankan, dunmi nibe oba nla Yah robbi koma s'oba meji ti momo, l'oba tiwon npe l'olohun Toba j'ese ti emi tinse, t'iyen fema dina ati gb'ore Emi nf'akoko yi toro, aforijin lodo re o allah Eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o Maf'ikankan, dunmi nibe oba nla Bee, mo l'awon nkan l'afojusun repete, nkan to wumi lokan pe kin ni O wumi kin nile pupo timo ko o, pelu ile ise topo repete Kin mari bukata gbo l'agbo dale o, kemi ma f'ewu ogbo agba t'ore Eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o Maf'ikankan, dunmi nibe oba nla Mo kepe e olohun mi, mo kepe e olohun mi, Olohun jowo wa rami kale, majen r'isoro Mo kepe e olohun mi, olohun jowo wa rami kale, majen r'isoro, naam Ogun k'eda le koma leba, k'eda fa koma to'rawon Iyen o wumi wa rami kale, maje nri'soro, olohun oba Mo kepe e olohun mi, olohun jowo wa rami kale, majen r'isoro Allah, je k'enu mi t'oro ninu ebi wa, Ma fami seyin ninu egbe kin tayo Agbega lemi nfe, wa famisoke, oba alaranse, olohun oba Mo kepe e olohun mi, olohun jowo wa rami kale, majen r'isoro Emi o sope owo o je nkan, miio de gbe'yi fun'le aye j'orun lo Sungbon owo l'ale fise pupo n'nu ise ore toni kama se, mofe ma t'ore Mo kepe e olohun mi, olohun jowo wa rami kale, majen r'isoro Mashaallah, oluwa mi, oriyomi lemi nje, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo Gbogbo ireti oore, je o tomi lowo ooo oti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo ha Mote f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo Gbogbo ireti oore, e o tomi lowo o, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo A leni ma deyin ma deyin ota ile ton o fe ka r'ibi mi mo Kos'iru áàlò t'ale se, kotun kin tewon lorun, bi k'ama se wa laye mo, lori loju ota wa Mio ni ku f'ota yo lailai, ma gbe'le aye seun rere o Moti f'oro ota gbogbo, fi l'oluwa lowo won gbe Moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo Gbogbo ireti oore, e o tomi lowo o, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo Seri ibanuje ota nipe, won nrimi pe mo cute Mio toro óbè tun gb'abo, losile awon eyan won Kobe kiwon le so pe ebi pami de ile odo won Atije atimu mi, mafi l'otami lowo, awon oro mi gbogbo, lowo oluwa lo ngbe Allahumma ina, aj-aluka fii, nuh-rihim Wa naudzu bika min, shururihim Allahuma akfinihim, bima shi-ita, allahuma anta a-duhdi Wa anta nasriy, bika ajulu wa bika, asuulu Wa bika uqotil, hasbuna Laha, wa ni-imal wakeel Moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo Gbogbo ireti oore, e o tomi lowo o, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo Ok, eti e gbo, wona enemy mi da? won ti wo'gbo, won ti ra m'aye Awon abinu eni da now? won ti wo'gbo, won ti ra m'aye Awon amoni seni da? Won ti wogbo, won ti ramaye Awon ota ologo da? Won ti wo'gbo, won ti ra m'aye Awon ápání máyo'dà? Won ti wo'gbo, won ti ra m'aye Tojepe loru na ma nfase ja? Won ti wo'gbo, won ti ra m'aye Ise ti ati nsebo lati ipile wa, kole da ti ati nbabo lati ibere wa o Eyi toku tota ndina ma salai shio, sebaje mafe gbayi nidi ibaje o Da'na súnwon konma file r'aye t'awa mo, nitoripe B'olohun se nsore e fun eru (Ota ngbogun ati tuka, yes Ani b'olohun se nsore e fun eru, ota ngbogun ati tuka Awa gbeke lolohun, ota ngbogun ati tuka B'ase gbeke lolohun, ota ngbogun ati tuka Eyin e ma wo'ran, e file o, ise lo gba o, fe s'eru ku niyen Oya, so p'otami yeye aye e, yeyee, yeye aye e Bimose nrije rimu kole ye e, ko lee, kole ye Bimose nri t'owo se kole ye e ko lee, kole ye Bimose ntoju ayemi, kole ye ko lee, kole ye Gbogbo lilo bibo mi kole ye e, ko lee, kole ye B'awon aye se nfemi kole ye e, ko lee, kole ye Amóni séni ota ile, ko lee, kole ye Olohun Mafi'koro simo o, mafi'koro simo, mafi'koro simo, mafi'koro simo Adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan Mafi'koro simo o, mafi'koro simo, adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan Opo oore eda laye o,lonyi s'ibanuje Olohun ilahi, ma mase t'awa be Towo batie wa wa, t'alafia o basi Kini igbadun owo, se ka l'ore èdé ni Ore ti o po dale oo, ore ti o po dale, olohun lemi fe Mafi'koro simo o, mafi'koro simo, adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan Won ni b'eye ègà kole o, yio f'enu re tu tan Sebi funra ólókùnrùn, lo nfenu re pe iku, oore ti mo nfe o, pe kose ilahi Toba ma dinira, dakun ba ns'atunse, toba semi bimo se fe o, ope mi o nitan Mafi'koro simo o, mafi'koro simo, adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan MashaAllah, moti nj'eni aponle o, maje npada wa te Aye npemi s'ariya, t'owo pelu ebun nla, won nsemi l'anu, won a tun s'adua funmi Mo l'olohun ma lase, loba sina anu, laba tun se'dera o, k'opeyemi le tele Mafi'koro simo o, mafi'koro simo, adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan Oriyomi, mo dupe f'awon fans, ton nf'owo ra data Adupe f'awon fans, ton nf'owo subscribe Adupe f'awon fans, ton, nfojojumo lo skit Ope to seyin fans, te nf'owo ra cd, bee Pelawon fans kan, ton npewa s'ode ere ton nawo, akanni, adua mi nipe o, k'olohun tunma se'bukun Oba o ni dawo ola duro Gbogbo be senri temi ro o, lolohun a ma ro'jo ike Oba oni dawo ola duro Gbagbo bese nfimi s'okan l'olohun a ma se'dunnu Oba oni dawo ola duro Hajji ibraheem dende, alase ibd ajao Oba oni dawo ola duro Sheu ganiyu akewushola olohun ni idahun s'adua Oba oni dawo ola duro Hajji razak arolat mi, ágbã owo tonpe l'àgbà awo Oba oni dawo ola duro Akeweje iseyin, baba adini of nigeria, oba oni dawo ola duro Alhaji lukman mi o, omo shittu zangallo zanga Oba oni dawo ola duro Alhaji ridwaanullahi, olamilekan dansokoto Oba oni dawo ola duro Akanmu agba omo bakare o, hajji rashidi agunwa Oba oni dawo ola duro Hajji saheed omo olayode o, akan'o oko ejire, oba oni dawo ola duro Omo agbaje shereefdeen mi, ola salam ni okan ni, oba oni dawo ola duro Babatundé ibon, abdul majeed l'olufimo, oba oni dawo ola duro Mio je gbagbe awon manager mi, tajo nse tofi ndun to ndan, oba oni dawo ola duro Ayesoro innocent ahmed, baba aliyah oko nafisat Oba oni dawo ola duro Adisa ade emir mi, ayomide ismaheel, oba oni dawo ola duro Owolabi lukman mi, baba fausat anisere, oba oni dawo ola duro Irawo toyeeb olamilekan, steady boy akorin ni Oba oni dawo ola duro
Writer(s): Oriyomi Kehinde Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out