Credits

PERFORMING ARTISTS
Reminisce
Reminisce
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Remilekun Safaru
Remilekun Safaru
Songwriter
Olawale Isaac Ayoola
Olawale Isaac Ayoola
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Reward
Reward
Producer

Lyrics

[Verse 1]
Ko le kupe, ko le hook
300, mo ni army to ma cook
Binu wọle bi Baddo Magodo brooks
O ma kari gbogbo cranny, gbogbo nooks
Listen! I have never served you none of those cheap flows
OG apparatus, mo ni cheat code
Flows to lomilara rọmurọmu bi ti hippo'
There can only be one Ọja D, echo
[PreChorus]
Ko le kupe, ko le hook
Ko le kobo, ko le wash
Ẹni to jabo lo lose
Ko le runle ko le dust
Ko le lana ko le burst
Gbogbo tilẹ l'ọn ṣi n rush
Ko le kogbawọle, bọbọ no go die until e off, listen
I now do this in my free time
Ti n ba jaye tan ti mo dẹ ni mean time
Ma lọ disturb mi fun gbẹdu rara, ọmọ this time
Gba dani bi igi relay in the mean time
[Chorus]
E dẹ le bajẹ, mo ni ko le bajẹ, ani ko le bajẹ
E dẹ le kupe, mo ni ko le kupe, ani ko le kupe
Ani ko le yiwọ, mo ni ko le yiwọ, ani ko le yiwọ
E dẹ le daru, mo ni ko le daru, ani ko le daru
Tori mo fẹ gawu o
[Verse 2]
Over the years fun wọn ni hoolala
Many men t'ọn lọ gbegẹ si gba bulala
Say this every time, see finish is not allowed
I been by my lonely, man I no dey roam about
Out when I'm outside, chill when I'm chilling
Dollar wa lapo, e dey house no be shillings
Rap ni••z wọn se balabala catching feelings
Ye, bawo niyẹn ṣe kan mi lọ mu ceiling
[PreChorus]
Ko le kupe, ko le hook
Ko le kobo, ko le wash
Ẹni to jabo lo lose
Ko le runle ko le dust
Ko le lana ko le burst
Gbogbo tilẹ l'ọn ṣi n rush
Ko le kogbawọle, bọbọ no go die until e off, listen
I now do this in my free time
Ti n ba jaye tan ti mo dẹ ni mean time
Ma lọ disturb mi fun gbẹdu rara, ọmọ this time
Gba dani bi igi relay in the mean time
[Chorus]
E dẹ le bajẹ, mo ni ko le bajẹ, ani ko le bajẹ
E dẹ le kupe, mo ni ko le kupe, ani ko le kupe
Ani ko le yiwọ, mo ni ko le yiwọ, ani ko le yiwọ
E dẹ le daru, mo ni ko le daru, ani ko le daru
Tori mo fẹ gawu o
[Outro]
Ko le kupe, ko le hook
Ko le kobo, ko le wash
Ẹni to jabo lo lose
Ko le runle ko le dust
Ko le lana ko le burst
Gbogbo tilẹ l'ọn ṣi n rush
Ko le kogbawọle, bọbọ no go die until e off, listen
I now do this in my free time
Ti n ba jaye tan ti mo dẹ ni mean time
Ma lọ disturb mi fun gbẹdu rara, ọmọ this time
Written by: Olawale Isaac Ayoola, Remilekun Safaru
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...