Credits

PERFORMING ARTISTS
Db Comic
Db Comic
Performer
Bada Damilola
Bada Damilola
12-String Acoustic Guitar
COMPOSITION & LYRICS
Bada Damilola
Bada Damilola
Songwriter

Lyrics

Oluwa a ma r\'ise yin o,
Oluwa a ma r\'owo yin o,
Awon toti gan wa tun was f\'ola wa toro,
Oluwa a ma r\'owo yin o,
Oluwa a ma r\'ise yin o,
Awon to ti yo wa tun wa f\'ola wa toro,
O mama se eledumare o,
O mama se o alatileyin o,
Ani bi ki ba se\'fe re o,kini nba ma wi,
O mama se o eledumare o,mo mama dupe dupe alatileyin,
Ani bi ki ba se\'fe re o,kini nba ma wi,
CHRS:Oluwa a ma r\'ise yin o(a ma r\'ise yin baba),
Oluwa a ma r\'owo yin o (a gbe o ga baba nla),
Awon to ti gan wa tun wa f\'ola wa toro,
Oluwa a ma r\'ise yin o,
Oluwa a ma r\'owo yin o (a gbe o ga),
Awon to ti yo wa tun wa f\'ola wa toro,
Bi ko ba se Iwo Jesu to duro timileyin,
Eniyan duro lati ba Mija,
Won Fe sheleya mi/2ce,
Oluwa a ma r\'ise yin o,
Oluwa a ma r\'owo yin o,
Awon toti gan wa tun was f\'ola wa toro,
Oluwa a ma r\'owo yin o,
Oluwa a ma r\'ise yin o,
Awon to ti yo wa tun wa f\'ola wa toro,
CALL:Gbogbo awon ta ti ranlowo,tan se bi olorun ko wa tanbi,
RESP: Awon to ti gan wa tun wa f\'ola wa toro,
CALL:Gbogbo awon to ti ro wa pin to\'n sebi olorun ko wa tanbi,
CALL:Ibi e foju si ona o gbabe,moti lo mo yin lowo o,
Awon to ti yo wa tun wa f\'ola wa toro,
Awon to ti gan wa tun wa f\'ola wa toro.
Written by: Bada Damilola
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...