Letras

Yo! Yo Rexxie pon this one Shebi tele tele, lama fo fun won wipe K'oma wa l'oru, toripe awa ti jade Amo ni sinyi o Ton ba wa losan, ton ba wa loru Awa n be ni be, awa o de le fo fun won Toripe awa tingasa, awa o de le sa fun won Aye yi o le o (aye yi o le) Aye lo m'aye le (aye lo m'aye le) Ninu aye lo ti di f'aye, aye lo m'aye le (Aye lo m'aye le) Aye yi o le o (aye yi o le) Aye lo m'aye le (aye lo m'aye le) Ninu aye lo ti di f'aye, aye lo m'aye le O n pe oku iya yi ni (eyin le ma sin iya yin) Oku your mother (eyin le ma sin iya yin) Oku momsi yin (eyin le ma sin iya yin) Oku your mama (eyin le ma sin iya yin) Nigba tin jale Tin mi o ba teni kan je, ti mo ni ti're ma da Wo ko n binu ori lasan Ori ma mu won Owo ma ba won Ti olorun ba ti gba'dura mi, bukata mi a fu'ye Aye yi o le o (aye yi o le) Aye lo m'aye le (aye lo m'aye le) Ninu aye lo ti di f'aye, aye lo m'aye le (Aye lo m'aye le) Aye yi o le o Aye lo m'aye le Ninu aye lo ti di f'aye, aye lo m'aye le Ninu aye lo ti di f'aye, aye lo m'aye le (yo!) Aye yi o le o Aye lo m'aye le (yo Rexxie one this one) Ninu aye lo ti di f'aye (yo!) Aye lo m'aye le Yo! Yo! Spirimix
Writer(s): Azeez Adeshina Fashola, Chisom Ezeh Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out