Letra

Edumare Je n r'ayo fi saye Onibuore J'ayo bami kale Ma gba'yo lowo mi eledumare Ma n je f'ikoro se ile aye Ma ma ma ma gb'ayo lowo mi eledua o Ma je f'ikoro saye Kayo mi po Kayo mi po daale Ebe ni mo be o Ani kayo mi po Kayo mi po daale Ebe ni mo be o Ohhhh Eleeedumare Eleeedumare Ma gba'yo lowo mi Eleeedumare Eleeedumare Ma mase gb'omo lowo mi Dami san Dami si F'ayoyemi Dami si oohh Dami si oohh F'ayoyemi F'ayoyemiiii Eledumaaare Eledumare oohhhhhh Eledumaaare Ma gb'omo lowo mi F'ayo kunu miii F'ayo kunu miii F'ayo kunu miii J'ayo bami daale Eledumaaaaaare Ma gba'yo lowo mi Eledumaaare Abiyamo ti n gb'omo re lofin Gbohun miii Baba Gbohun miii Eledumaaare Eledumaaare F'ayo kunu miii F'ayo kunu miii Ma gba'yo lowo mii Eledumaaare F'ayo kunu miii Eledumaaare Eledumaaare
Writer(s): Teledalase Ayomide Ogundipe Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out