Letra

Oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh Oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh-oh, yea-yea (Mad-Madaroad) Oh-oh-oh-oh-oh-yea-uh-uh-oh Oh-oh-oh-uh-uh Yea, eh-eh Say, I don't force it I just let the Spirit lead, 'cause I know Yes, I know You are with me all the way My Father, My Father, Ọlọrun ti ko kí ń yipò padà Ọrọ ayé mí ọwọ ẹ lowa, ìwọ nìkan ní mo gbẹkẹmile o, ah-ah (ẹru ògo rẹ ńbámí) Ẹlẹwa Ògo, hm, Àdàbà Mímọ, jọwọ, bale mí o, oh-oh (emi ọmọ rẹ ree) Mo tún dúró síwájú rẹ bí mo ṣe má ńṣe Ẹmí-Mímọ, jọwọ, wá gbé mí fo oo Mo fẹ ga nínú wọn (gbà mí gbọ) Má ṣe gbàrà lewọn, má ṣe gbẹkẹle'nìyàn Ìgbẹ́kẹ̀le ènìyàn asán bansa, ye-ye o Má ṣe gbàrà lewọn, dákun, má ṣe gbẹkẹle'nìyàn Ìgbẹ́kẹ̀le ènìyàn asán bansa, yeye-oh Ìrìn yí mọọ, má lọ lofo, ní mo ṣe d'ẹsẹ Ọlọ́run mí mú o, uh (Ní mo ṣe gbà Ọlọ́run mí mú ṣinṣin) Bí Olùwà ṣe ń ṣ'ọla ìyẹn nínú ọlá àt'ayọ Bẹ ní yí o tún ṣ'ògo, ohh, Ọlọrun mí ògo My Father, My Father, Ọlọrun ti ko kí ń yipò padà Ọrọ ayé mí ọwọ ẹ lowa, ìwọ nìkan ní mo gbẹkẹmile o, ah-ah (ẹru ògo rẹ ńbámí) Ẹlẹwa Ògo, hm, Àdàbà Mímọ, jọwọ, bale mí o, oh-oh (emi ọmọ rẹ ree) Mo tún dúró síwájú rẹ bí mo ṣe má ńṣe Ẹmí-Mímọ, jọwọ, wá gbé mí fo oo Mo fẹ ga nínú wọn (gbà mí gbọ) Má ṣe gbàrà lewọn, má ṣe gbẹkẹle'nìyàn Ìgbẹ́kẹ̀le ènìyàn asán bansa, ye-ye o Má ṣe gbàrà lewọn, dákun, má ṣe gbẹkẹle'nìyàn Ìgbẹ́kẹ̀le ènìyàn asán bansa, ye-eh-oh (Sunshine on the mix)
Writer(s): Barry Jhay Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out