Letra

Mo má dúpẹ' Bàbá ooo Elẹrú mí yín o (it's Bizzouch) Mo má dúpẹ', oo-eh Oii-nih Baba, I see I see the weather too coming through for me With Your power, I dey see front oo, eh-eh You do me wetin, nobody fit to do-do for me Oii-nih Oh-oh Orí adé ló ṣé mí oo, oh na-na Ṣé bí 'wo lónì ńmá j'ọba, eh-ee Orí mí tètè lá, k'orí ọlọlá máà pé ẹ rán níṣẹ̀ o Ẹ'dá mí tètè lá, k'ẹ'dá ọlọ́lá máà pé ẹ o Mà ṣọ'pẹ F'ore tó ṣé láyé mí, òpọ púpọ', ye o Ọba ayérayé, ráyé Mà ṣọ'pẹ (ooh-) F'ore tó ṣé láyé mí o, opọ púpọ', ye o Ọba ayérayé, ráyé Say me, I don't know, know Say me, I no know, know Daddy, why You love me so? Walahi Why You love me so oo? I don't know, I no know Me, I no know o Why you love me so oh? Why you love me so oo? (Oii-nih) Bàbá Mímọ' o Orí adé ló ṣé mí oo, eh-eh-eh, ee Ṣébí 'wo lónì ńmá jọba Orí mí tètè lá, k'orí ọlọ́lá má pé ẹ rán níṣẹ̀ o K'ẹda mí tètè lá, k'ẹda ọlọ́lá má pé ẹ o Mà ṣọ'pẹ F'ore tó ṣé láyé mi, o pọ púpọ', ye oo Ọba ayérayé, ráyé Mà ṣọ'pẹ (ooh-) F'ore tó ṣé láyé mi o, o pọ púpọ', ye o Ọba ayérayé, ráyé, 'ayé (It's STG)
Writer(s): Oluwakayode Balogun Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out