album cover
Jegele
album cover
Jegele è stato pubblicato il 3 luglio 2020 da YBBM come parte dell'album Jegele - Single
3 luglio 2020
EtichettaYBBM
BPM199
Melodicità
Acousticità
Valence
Ballabilità
Energia

Testi

[Intro]
DaBeat Handle
Faliuli fakirh lailu samaru
Qdot lorukọ mi
[Verse 1]
To o ba ti lowo mọ
Fadeyi ẹ gan-an o le loro mọ
No time for "baba baba" fun ọmọ yahoo ti o gbowo mọ
Maruwa to fẹ wọ caterpillar ni engine rẹ ma kọ gbona na
Banusọ, ma beniyan sọ oh, aye le
Ohun taja ri to n gbo ko teyi taguntan fi n ṣeranwo
Aguntan o ni sun saarin aja ko ma fara keegbọn
O ya ma lọ trust nobody tori aye yii ti gbẹgẹ
Kokoro ti n jẹfọ abẹ ẹfọ ni n gbe, ọdẹ ta fi ṣọle lo pẹran wa jẹ
[Chorus]
Iṣubu kekere kan ṣẹlẹ si mi wọn ro pe mi o le dide mọ
Just because say I fall dem think say I no go rise again
Jegele, jegele, jegele (Jegele)
Jegele, jegele, jegele (Jegele)
Jegele, jegele, jegele (Jegele)
Jegele, jegele, jegele
[Verse 2]
Learn to trust no one but yourself
Ojiji ẹni fini silẹ ta ba wa lokunkun (Aye)
Wọn ma ni ko wọja ni ihoho ko lọ ra bata, ṣe bata lo yẹ
Ohun ta ba fabosi ko jọ, ko ki n tọjọ
Tori ohun to ba gbin lo ma ka oh
You say you no be my enemy
But you dey wish me bad oh (But you dey wish me bad oh)
Ẹni ta ni ko fẹni loju, ata barbecue lo ko sẹnu
[Chorus]
Iṣubu kekere kan ṣẹlẹ si mi wọn ro pe mi o le dide mọ
Just because say I fall dem think say I no go rise again
Jegele, jegele, jegele (I no die)
Jegele, jegele, jegele (Iyalaya yin, jegele)
Jegele, jegele, jegele (I still dey, jegele)
Jegele, jegele, jegele
[Verse 3]
Mo ti gbọn mi o finu tan eniyan mọ
Agbara Baba mi loke lo n pa mi mọ
Aye ta n gbe yii o le, awọn ọmọ Adamọ lo mu ile-aye koko
Kifibiru bu waji, kiri bu waji, kiribu
Alola, firi kina waka taratu jalalu (Gawati za-zaka)
Alola, firi kina teri moka (Eri ohh)
Fali uli, fakiri lailah samaru
Eli mi, eli mi failiru januza
Eli wana karifah sen seburi wala'ka buriwaka buriji
Ada wa si, ada wa sa
Ọlọrun anọbi Jesu
Alola fi, Sellimota y'ona pupọ
'Elimota, see gbege
Adaba mi ah, funfun ma ni, aso adura mi funfun ma ni
[Outro]
Hey, who's here?
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...